Ọjọ́ ìkéde lòdì sí kíkó àwọn ènìyàn lọ sí ìlú onílùú lọ́nà àìtọ́ ní orílẹ̀-èdè Europe (EU anti-trafficking day)

(Àtúnjúwe láti EU anti-trafficking day)

EU Anti-Trafficking Day jẹ́ ọjọ́ tí wọ́n yà sọ́tọ̀ láti kéde lòdì sí wíwọ ìlú lónà àìtọ́. Ọjọ́ kejìdílógún oṣù ọ̀wàwà ni ọjọ́ ìyàsọ́tọ̀ fún ìpolongo yìí. Ìgbìmọ̀ Europe ni wọn dá a sílẹ̀ pẹ̀lú èròngbà áti jẹ́ kí àwọn ènìyàn mọ̀ nípa ewu tí ó wà nínú kíkó àwọn ènìyàn wọ ìlú lọ́nà àìtọ́ àti títẹnumọ́ ẹ̀tọ́ àwọn afarapa láti wá ìdájọ́ tótọ́.

Àwọn ènìyàn gbàgbọ́ pé àṣà ìkónilẹ́rú jẹ́ ohun tó tí kọjá lẹ́yì tí wọ́n fi òpin sí i. Àmọ́ ó ṣeni láàánú pé èyí kò rí bẹ́ẹ̀ rárá. Ní tòótọ́, ó jẹ́ ohun tí kò ní òde- òní, àmọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà tuntun ní wọn ń gbà mú àwọn èniyàn lẹ́rú, lílo ọmọ fún iṣẹ́ ọmọ ọ̀dọ̀, lílo ọmọdé fún ẹ̀ṣó ológun, títi ọmọdé sí ìgbéyàwò tipátipá, àti bẹ́ẹ̀ lọ kò gbẹ́yìn[1][2][3]. ó jẹ́ ọjọ tí wọn yà sọ́tọ̀ láti ṣe ìrántí àwọn tí ó farakááṣá nínú kíkó àwọn ènìyàn láti ìlú kan sí òmíràn lọ́nà àìtọ́ human trafficking[4] Ìdí fún ìpolongo yìí ni lati ṣe àfikún òye, ìmọ àti ìmúlò tó péye láàárí àwọn tí ó ń ṣiṣẹ ẹ̀ka yìí[5].

Ọjọ́ ìkéde lòdí sí kíkó àwọn ènìyàn lọ sí onílùú lọ́nà àìtọ́ ní orílẹ̀-èdè Europe wà láti ru àwọn ará ìlú sókè àti dẹ́kun ìwà Ọjọ́ ìkéde lòdí sí kíkó àwọn ènìyàn lọ sí onílùú lọ́nà àìtọ́ ní orílẹ̀-èdè Europe àti láàárín àwọn ènìyàn lápapọ̀.

Àwọn ìtọ́kasí.

àtúnṣe
  1. "EU Anti-Trafficking Day / October 18, 2022". AnydayGuide. Retrieved 2022-03-30. 
  2. "EU Anti-Trafficking Day: Working together to stop trafficking in human beings". ec.europa.eu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-30. 
  3. Roy, Heather (2021-10-18). "EU Anti-trafficking Day". Eurodiaconia (in Èdè Póláǹdì). Retrieved 2022-03-30. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. "EU Anti-Trafficking Day 2021". United Nations : UNODC Brussels Liaison Office (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-30. 
  5. "EU Anti-Trafficking Day Panel Discussion held in Nicosia". www.abbilgi.eu. Retrieved 2022-03-30.