Ìpínlẹ̀ Ìlàòrùn-Àrin
(Àtúnjúwe láti East-Central State)
Ipinle East Central je ipinle amojuto tele ni Nigeria. O je dida ni 27 May 1967 lati awon apa Agbegbe Apailaorun o si wa titi di 3 February 1976, nigbati o je pinpin si ipinle meji - Anambra ati Imo. Loni awon ipinle marun ni won wa nibi to wa tele: Anambra, Imo, Enugu, Ebonyi ati Abia. Ilu Enugu ni o je oluilu re nigbana.
Awon Gomina/Olumojuto Ipinle East Central
àtúnṣe- Ukpabi Asika, Administrator (1967 – July 1975)
- Anthony Ochefu, Governor (July 1975 – February 1976)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |