Eberechi Wike
Adájọ́ Eberechi Suzzette Wike (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìnlélógún oṣù karùn-ún ọdún 1972) jẹ́ Adájọ́ ní ilé-ẹjọ́-ńlá ti. Òun ni ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Rivers, Gómìnà Ezenwo Nyesom Wike láti ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2015.[1]
Eberechi Wike | |
---|---|
Wike at the Zonal Nutrition Summit in Port Harcourt | |
First Lady of Rivers State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2015 | |
Gómìnà | Ezenwo Nyesom Wike |
Asíwájú | Judith Amaechi |
Judge of the Rivers State High Court of Justice | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 14 February 2012 | |
Appointed by | Chibuike Amaechi |
Asíwájú | ?? |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Eberechi Suzzette Obuzor 24 Oṣù Kàrún 1972 Odiokwu, Ahoada West, Rivers State |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Ezenwo Nyesom Wike |
Àwọn ọmọ | 3 |
Àwọn òbí | Ikechukwu Obuzor |
Residence | Port Harcourt, Rivers State |
Alma mater | University of Science and Technology, Rivers State |
Profession | Lawyer |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "NASS Rivers State Caucus hails Justice Eberechi Nyesom-Wike as she marks her birthday". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-05-24. Retrieved 2022-02-23.