Edikang ikong
Ọbẹ̀ àwọn ẹ̀yà Efik
Edikang ikong jẹ́ ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ tí ó ṣẹ̀ wá láti àárín àwọn èyà Efik ti Ìpínlẹ̀ Cross River, àwọn èèyàn Ibibio ti Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ní apá Gúúsù mọ́ ilẹ̀ Gúúsù ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1][2][3][4] Wọ́n gbà pé oúnjẹ aládìídùn ni delicacy láàárín àwọn èèyàn Nàìjíríà kan, ó sì máa ń di ṣíṣè lásìkò ayẹyẹ tí ó ṣe pàtàkì.[5][6] Edikang ikong jẹ́ ọbẹ̀ asaralóooore tí ó sì wọ́n púpọ̀ láti sè, ó sì ti di ṣíṣe àpèjúwe pé àwọn olówó nìkan ni ó sábàá máa ń jẹ ẹ́ ní Nàìjíríà.[5] Ohun èlò tí wọ́n ń lò fún edikang ikong ni ògúnfe àti ẹja gbígbẹ, ẹran ìgbẹ́,edé, shaki, Kanda, ewé, gbúre, ugu, àlùbọ́sà, periwinkle, epo pupa, iyọ̀ àti ata.[1][5][7][8][9]
Lẹ́yìn ṣíṣè, edikang ikong sábàá máa ń di jíjẹ pẹ̀lú fufu, wheat flour, eba, tàbí iyán.[10]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedPulse 20152
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedUkpong 20162
- ↑ "Prepare Edikang Ikong With These 10 Easy Steps". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-24. Retrieved 2022-07-02.
- ↑ Online, Tribune (2019-12-28). "Why not delightsome Edikang-ikong soup?". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-02.
- ↑ 5.0 5.1 5.2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedIyobebe 20162
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedAgbenson 20142
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedInyese 20152
- ↑ "Edikang Ikong Recipe For Dummies". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-26. Retrieved 2022-07-02.
- ↑ joan (2015-05-20). "Recipe for an amazing Edikang Ikong Soup". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-07-02.
- ↑ "Edikaiakong Soup". Leadership Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-25. Retrieved 2019-04-19.