Egg of Life (fíìmù Nàìjíríà ti ọdún 2003)

Egg of Life jẹ́ fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà ti ọdún 2003, tó dá lórí ṣíṣe ìwòsàn fún ọmọ-ọba kan tó wà lójú ikú. Olùdarí fíìmù yìí ni Andy Amenechi, Kabat Esosa Egbon àti Ojiofor sì ló kọ ọ́.[1][2][3]

Àwọn akópa

àtúnṣe
  • Padita Agu bí i Nkem
  • Sam Ajah bí i Madu
  • Funke Akindele bí i Isioma
  • Ozo Akubueze bí i Ichie Arinze
  • Gazza Anderson bí i Segbeilo
  • Nina Bob-Chudey bí i Obiageli
  • Clarion Chukwura bí i Alufa
  • Pete Edochie bí i Igwe
  • Fidelis Ezenwa bí i Ogbuefi Nwabuzor
  • Ifeanyi Ezeokeke bí i Ikemefuria Snr
  • Nnadi Ihuoma bí i Chioma
  • Sabinus Mole bí i Amaka
  • Dike Ngwube bí i Ogogo
  • Somtoo Obasi bí i Omo Tuntun
  • Ebele Okaro bí i Lolo
  • Stanley Okereke bí i Okonkwo
  • Georgina Onuoha bí i Buchi

Ìsọníṣókí

àtúnṣe

Ọmọ-ọba kan ló wà ní ojú ikú, tó sì níló ẹyin àràmàǹdà tó ń mú ìyè wá. Ó sì níló kí ọ̀wọ́ àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin kan lọ inú-igbó láti gba ẹ̀mí rẹ̀ là, látàrí nǹkan tí adífá sọ.[4][5]

  1. "Andy Boyo, Andy Amenechi, Chika Onu, others inducted into CCFF". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-04-02. Archived from the original on 2022-07-31. Retrieved 2022-07-31. 
  2. izuzu, chibumga (2017-02-16). ""Egg of Life" vs "Igodo" - Which is your favourite classic epic movie?". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-07-31. 
  3. Egg of life. https://www.researchgate.net/publication/350790265. 
  4. Tv, Bn. "#BNMovieFeature: Watch Funke Akindele-Bello, Padita Agu & Nkiru Sylvanus in this Nollywood Classic "Egg of Life"". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-31. 
  5. Bassey, Rosemary (2021-08-07). "1990s Nollywood movies to reminisce on". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-01.