Emmanuel Iren

olorin ihinrere Naijiria ati Aguntan

Emmanuel Aniefiok Iren (wọ́n bí ní ojo kejidinlogun osu Ope,odun 1989) tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Emmanuel Iren jẹ́ oníwàásù àti olórin ẹ̀mí ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Òun ni olùdásílẹ̀Celebration Church International (CCI), èyí tí olú-ìjọ wọn wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ní Nàìjíríà.[2][3] Ní ọdún 2018, ó ṣàgbéjáde orin àkọ́kọ́ rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Kerygma, ní ọdún 2022, ó sì ṣàgbéjáde àwò-orin kejì rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Apostolos:Voice of Transition.[4][5]

Emmanuel Iren
Orúkọ àbísọEmmanuel Aniefiok Iren
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kejìlá 1989 (1989-12-18) (ọmọ ọdún 35)
Ìbẹ̀rẹ̀Akwa Ibom, Nigeria
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
  • pastor
InstrumentsVocals and drums
Years active2008–present

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Emmanuel Iren ní ojo kejidinlogun osu ope, odun 1989. Ìpínlẹ̀ Akwa Íbọm ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ló sì ti wá. Ó lo si ile ekọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní Saint Bernadettes Nursery and Primary School ní Ipaja, ní ìpínlẹ̀ Èkó.[6] Láti ibẹ̀, ó lọ sí Queen’s Choice Nursery and Primary School College ní Ikotun, ní ìpínlẹ̀ Èkó bákan náà ni o ti lo si ile iwe girama Doregos Private Academy láti kọ ẹ̀kọ́.[7]

Àtòjọ àwon orin rẹ̀

àtúnṣe

Àwo orin

àtúnṣe
Year of Release Title Details Ref
2018 Kerygma

(feat Outburst Music Group)

  • Recording Type: Live
  • No. of Tracks: 15
  • Format: Digital Download, Streaming
[8]
2022 Apostolos: Voice of Transition
  • Recording Type: Live
  • No. of Tracks: 13
  • Format: Digital Download, Streaming
[9][10]

Orin àdákọ

àtúnṣe
  • Grace Changes Everything (feat Sinach)
  • Overcome (feat E-Daniels)
  • Prophetic Chant (feat Nosa)
  • Fire On My Altar
  • The Glory (feat Outburst Music Group)
  • Yes To Your Will

Orin tó kópá nínú

àtúnṣe
  • Zoe (Odunayo Adebayo feat Emmanuel Iren)[11]
  • Bo Ta Jor (Prinx Emmanuel feat Emmanuel Iren)[12]

Àtòjọ àwọn ìwé rẹ̀

àtúnṣe
  • Leading Seeks You[13]
  • Purposefully[14]
  • Am I Being Fooled? FAQs about God, the Bible and Jesus Christ
  • Saving Grace
  • Come To Me Bible Book

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Akintomide, Marvellous (2023-06-02). "Nigerian Gospel Artists That Should Be On Your Radar". Zikoko! (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-10. 
  2. "‘We must have audacity to embrace vision regardless of culture’ says Emmanuel Iren of Celebration Church International". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-07. Archived from the original on 2023-05-15. Retrieved 2023-05-15. 
  3. Omoleye, Omoruyi. "#YNaijaChurch100: Mercy Chinwo, Banky W, Sam Adeyemi | See the 100 Most Influential People in Christian Ministry in Nigeria". YNaija. https://ynaija.com/church100-mercy-chinwo-banky-w-sam-adeyemi-see-the-100-most-influential-people-in-christian-ministry-in-nigeria/. 
  4. "Emmanuel Iren Features Sinach, Others In Apostolos Album". Independent Newspaper. https://independent.ng/emmanuel-iren-features-sinach-others-in-apostolos-album/. 
  5. Rapheal (2022-10-07). "Pastor Emmanuel Iren’s Apostolos makes waves". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-15. 
  6. admin (2023-02-01). "Biography Of Apostle Emmanuel Iren". Christian Gospel songs - Christian ebooks | Christiandiet (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-26. 
  7. Man, The New. "Biography of Apostle Emmanuel Iren". The New Man. Retrieved 2023-05-15. 
  8. Akindele, Bolu (2018-01-17). "[The Church Blog] Introducing Kerygma: The new sound of Lyrical Theology » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-10. 
  9. Mix, Pulse (2022-08-08). "Pastor Emmanuel Iren releases his debut album 'Apostolos'". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-15. 
  10. "Listen To Pastor Emmanuel Iren's Debut Album "Apostolos"". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-08-10. Archived from the original on 2023-05-15. Retrieved 2023-05-15. 
  11. Desk, NaijaMusic (2022-08-05). "Odunayo Adebayo ft Pastor Iren - Zoe". NaijaMusic (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-10. 
  12. S9, The Boss (2023-05-23). "Prinx Emmanuel – Bo Ta Joor Ft. Pastor Emmanuel Iren". Six9ja (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-10. 
  13. "Leading Seeks You". Goodreads (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-15. 
  14. "Emmanuel Iren Books. Amazon.com". www.amazon.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-16.