Sinach
Akọrin obìnrin
Osinachi Kalu Okoro Egbu,[1] Tí a mọ̀ gẹ́gẹ́ bí Sinach, àbí ní ọjọ́ ọgbọ́n oṣù kẹta ọdún 1972. Ó jẹ́ olórin ìlú Nàìjíríà, akọrin àti olórí olùsìn àgbà tí ó tí ń ṣiṣẹ́ fún bí ọgbọ́n ọdún.[2][3] Ó jẹ́ akọrin àkókò tó kọ́kọ́ de ipò Billboard Christian Songwriter chart fún ọ̀sẹ̀ méjìlá.[4] Ẹ̀mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní Wọ́n yan orin rẹ̀ ó sì gba orin tó dára jù lọ́dún ní 5i st GMA Dove Awards, èyí ni ó jẹ́ kí ó di ọmọ Nàìjíríà àkókò tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ.[5] Ní ọdún 2021 ó gba ìdánimọ̀ ní US congress ní ìgbà tí ó wà ní ìrìn-àjò ní United States tí Amẹ́ríkà.[6][7]
Sinach | |
---|---|
Sinach performing at Mosaiek Theatre in Johannesburg 2016 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Osinachi Kalu |
Ọjọ́ìbí | 30 Oṣù Kẹta 1972 |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Afikpo South, Ebonyi State, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Years active | 1994–present |
Labels |
|
Website |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Dove Awards name for King & Country top artist". ABC News.
- ↑ "Who is Sinach". Daily Media. DailyMedia Nigeria. 26 May 2016. Archived from the original on 26 December 2017. Retrieved 26 September 2017.
- ↑ "Sinach". 9999CarolSingers. Archived from the original on 6 June 2014. Retrieved 3 June 2014.
- ↑ Clarks, Jessie (5 June 2020). "Sinach Named Top Christian Songwriter For Twelve Weeks In A Row". TheChristianBeat.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 16 December 2020.
- ↑ "2020 Dove Awards: Sinach's Way Maker emerges song of the Year". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 3 November 2020. Retrieved 27 March 2021.
- ↑ "Sinach gets US Congress recognition". Businessday NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-04. Retrieved 2021-10-04.
- ↑ "Sinach teams up with friends for annual concert" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-04. Retrieved 2021-10-04 – via ((The_Punch )).