Emmanuel Nnamdi Uba
Olóṣèlú Nàìjíríà
Emmanuel Nnamdi Uba jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.
Emmanuel Nnamdi Uba | |
---|---|
Aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù karún ọdún 2011 | |
Asíwájú | Ikechukwu Obiorah |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kejìlá 1958 Enugu, Enugu State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Why I opted for Labour Party, by Andy Uba". The Nation (Nigeria). 2009-12-31. Retrieved 2011-06-15.