Eré Òṣùpá jẹ́ erémọdé tí àwọn ọmọdé máa ń fi dára yà tàbí kẹ́kọ̀ọ́ lálẹ́ nígbà tí ìmọ́lẹ̀ òṣùpá bá tàn láyé àtijó. Àwọn ọmọdé àdúgbò á máa kó ara wọn jọ lálẹ́ láti dára yá nípa ṣíṣe àwọn eré òṣùpá bíi; bojúbojú, Onídè Ré àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Nígbà mìíràn ẹ̀wẹ̀, àgbà àdúgbò kan ni yóò kó àwọn ọmọdé jọ láti pa Àlọ́ fún wọn. Ó lè jẹ́ Àlọ́ Àpamọ̀ tàbí Àlọ́ Àpagbè . Ìdárayá, ẹ̀kọ́ àti Ọgbọ̀n kíkọ́ ni àwọn wọ̀nyí wà fún.[1]

Àwọn Eré Òṣùpá Ilẹ̀ Yorùbá tí àwọn ọmọdé máa ń ṣe láyé àtijó

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Awala, Verity (2016-03-04). "9 Childhood Games Anyone Who Grew Up In Nigeria Can Never Forget". Information Nigeria. Retrieved 2020-01-24. 

https://www.independent.ng/cultural-education-stimulates-mental-development-children-adesanya/