Ere MKO Abiola
Olurotimi Ajayi ni o gbé ere MKO Abiola láti ma jé iranti Oloye Moshood Abiola, oloselu kan ti gbogbo eniyan gba bi olubori ninu ibo 1993 ni Naijiria. Iduro ere náà to ìwon esè merindilaadota(46 feet), a se afihan ere naa ni 12 June 2018 lakoko ijọba Gomina Akinwunmi Ambode .
Nípa Abiola
àtúnṣeMoshood Kashimawo Olawale Abiola, ti gbogbo eniyan mò si MKO Abiola (24 August 1937 – 7 July 1998) je onisowo ati oloselu. O dije du ipo aarẹ orilẹede Naijiria ni ọdun 1993, gbogbo eniyan sì ni wọn ka si gẹgẹ bi olubori botilẹj ẹpe esi idibo náà ko jade. Lọ́dún 1994, wọ́n mú un, wọ́n sì fi í sẹ́wọ̀n lórí ẹ̀sùn ìwà ọ̀daràn lẹ́yìn tó kéde ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ orílẹ̀- èdè Nàìjíríà . MKO Abiola ku ni ojo keje osu keje odun 1998, ojo ti o ye ki won tu sile ninu tubu. Iku rẹ jẹ awọn iṣẹlẹ ifura, lakoko ti iwadii ikú rè fihan pé Abiola ku nitori ikọlu ọkan, Ààre ologun Sani Abacha sọ pe wón lu pa ni.
Idi ti a fi gbé ere náà kalè
àtúnṣeNi iranti igbesi aye tí Abiọla fi lelẹ, ijọba ipinlẹ Eko nipasẹ gomina Akinwunmi Ambode ṣe afihan ere MKO Abiola ni ọjọ 12 oṣu kẹfa ọdun 2018 - deede ọdun marundinlọgbọn lẹhin ti o jáwé olubori nínú idibo
ni 12 June 19-arẹ ni Ojotìpínlè ti Eko. [1] GominAmbodeaa sọ pe ere naa yoo jẹ irantigbe-aye n Abiọla atipá ribiribi rè nínú i oṣelu Naijiria.
Awon aworan
àtúnṣe-
A wide view of the Statue of Chief M.K.O Abiola in Abiola Gardens, Ojota, Lagos-Nigeria
-
MKO Abiola Gaden
-
MKO Garden, Ojota, Lagos
-
A garage in Ojota
-
A garden at Ojota