Ernesto Zedillo je Aare orile-ede Meksiko tele.

Àdàkọ:Àwọn ààrẹ ilu Mẹ́síkò

Àdàkọ:Family name hatnote

Ernesto Zedillo

Aarẹ Zedillo ni ọdún 1999.
61st Àárẹ̀ ile Mẹ́síkò
AsíwájúCarlos Salinas de Gortari
Arọ́pòVicente Fox
Secretary of Public Education
In office
7 January 1992 – 29 November 1993
ÀàrẹCarlos Salinas de Gortari
AsíwájúManuel Bartlett
Arọ́pòFernando Solana
Secretary of Programming and Budget
In office
1 December 1988 – 7 January 1992
ÀàrẹCarlos Salinas de Gortari
AsíwájúPedro Aspe
Arọ́pòRogelio Gasca
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Ernesto Zedillo Ponce de León

27 Oṣù Kejìlá 1951 (1951-12-27) (ọmọ ọdún 72)
Mexico City, Mexico
Ẹgbẹ́ olóṣèlúInstitutional Revolutionary Party
(Àwọn) olólùfẹ́
Àwọn ọmọ5
Àwọn òbíRodolfo Zedillo Castillo
Martha Alicia Ponce de León
ResidenceNew Haven, Connecticut, U.S.
EducationNational Polytechnic Institute (BA)
Yale University (MA, PhD)
Signature

Ernesto Zedillo Ponce de León CYC GColIH GCMG (Pípè: [eɾˈnesto seˈðiʝo]; jẹ ẹni tí a bi ni ojo ketadinlogbon oṣù Kejìlá ni ọdún 1951 o si jẹ olóṣèlú ati onimọ ọrọ ajé. Ọ je ààrẹ ilu Mẹsiko lati ọjọ kini oṣu Kejìlá odun 1994 sí ọjọ ọgbọn osu kẹtala odun 2000, ọ sí je ààrẹ to kẹyin ninu ijoba awon aare tó jẹ ọmọ ẹgbẹ Institutional Revolutionary Party.