Ààrẹ ilẹ̀ Mẹ́ksíkò

(Àtúnjúwe láti President of Mexico)

Ààrẹ ilẹ̀ Mẹ́ksíkò (lonibise ni ede Spani Ciudadano Presidente Constitucional de los Estados Unidos Mexicanos) ni olórí orílẹ̀-èdè àti Olórí ìjọba ilẹ̀ Àwọn Ìpínlẹ̀ Mẹ́ksíkò Aṣọ̀kan.

Constitutional
Citizen President
the United Mexican States
Standard of the President of Mexico
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Felipe Calderón

since December 1, 2006
ResidenceLos Pinos
Iye ìgbàSix years (sexenio),
single term
Ẹni àkọ́kọ́Guadalupe Victoria
FormationOctober 10, 1824
Websitepresidencia.gob.mx/