Esie Musium
Esiẹ Musium jẹ ile ọnọ ni Esiẹ, Ipinle Kwara, ni orile ede Nàìjíríà.
Esie je ilu Igbomina ni ijoba ibile Irepodun LGA ni ilu Kwara. Esiẹ Musium ni Ile ọnọ akọkọ ni orile ede Nigeria ti a da silẹ ni ọdun 1945 lati gbe ọkan ninu awọn iṣura nla julọ ti a ti fi silẹ fun ẹda eniyan, Awon Ere Esie.
Ile ọnọ yi jẹ akọkọ ti won da silẹ ti won si ṣii ni ọdun 1945.[1] Ni igba kan ri, Ile musiọmu yii ni ohun to ju ẹgbẹrun awọn aworan ibojì tabi awọn aworan ti o nsoju eniyan.[2]
O jẹ ile ọnọ ti o ni akojọpọ awọn aworan ere ti awon elede geesi n pe ni soapstone ti o tobi julọ ni agbaye.[3] Ni awọn akoko ode oni, ile musiọmu Esie ti di aye ẹsin iṣẹṣẹ ati igbalejo ajọdun kan ni oṣu Kẹrin ni ọdọọdun.[4]
Àwọn itọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "(PDF) NIGERIA SCULPTURAL TRADITION AS VIABLE OPTION FOR TOURISM PROMOTION: AN ASSESSMENT OF ESIE MYSTERIOUS STONE SCULPTURES". ResearchGate (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-21.
- ↑ "Esie: Nigeria’s first museum, generates N10,000 monthly". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-21.
- ↑ "Esie Museum". All Africa. Retrieved 1 February 2013.
- ↑ "Tourism". Nigerian Embassy, Budapest, Hungary. Retrieved February 1, 2013.