Esie Musium

(Àtúnjúwe láti Esie musium)

Àdàkọ:Infobox museum

Esiẹ Musium jẹ ile ọnọ ni Esiẹ, Ipinle Kwara, ni orile ede Nàìjíríà.

Awon Ere Esie).

Esie je ilu Igbomina ni ijoba ibile Irepodun LGA ni ilu Kwara. Esiẹ Musium ni Ile ọnọ akọkọ ni orile ede Nigeria ti a da silẹ ni ọdun 1945 lati gbe ọkan ninu awọn iṣura nla julọ ti a ti fi silẹ fun ẹda eniyan, Awon Ere Esie.

Ile ọnọ yi jẹ akọkọ ti won da silẹ ti won si ṣii ni ọdun 1945.[1] Ni igba kan ri, Ile musiọmu yii ni ohun to ju ẹgbẹrun awọn aworan ibojì tabi awọn aworan ti o nsoju eniyan.[2]

Esie musium ti a da sile ni odun 1945 ni ijoba ibile Irepodun ilu Kwara.

O jẹ ile ọnọ ti o ni akojọpọ awọn aworan ere ti awon elede geesi n pe ni soapstone ti o tobi julọ ni agbaye.[3] Ni awọn akoko ode oni, ile musiọmu Esie ti di aye ẹsin iṣẹṣẹ ati igbalejo ajọdun kan ni oṣu Kẹrin ni ọdọọdun.[4]

Adaparọ kan wa pe ni awọn ọdun to ti pẹ sẹyin, awọn olugbe ilu naa ṣe ẹṣẹ nla ti ãrá si sọ awọn eniyan naa di okuta.

Àwọn itọ́kasí

àtúnṣe
  1. "(PDF) NIGERIA SCULPTURAL TRADITION AS VIABLE OPTION FOR TOURISM PROMOTION: AN ASSESSMENT OF ESIE MYSTERIOUS STONE SCULPTURES". ResearchGate (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-21. 
  2. "Esie: Nigeria’s first museum, generates N10,000 monthly". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-21. 
  3. "Esie Museum". All Africa. Retrieved 1 February 2013. 
  4. "Tourism". Nigerian Embassy, Budapest, Hungary. Retrieved February 1, 2013. 

Àdàkọ:Museums in Nigeria

Àdàkọ:Coord missing


Àdàkọ:Nigeria-museum-stub