Eso Dike

Òṣèrẹ́kùnrin ilẹ̀ Nàìjíríà

Okolocha Esowese Dike tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bíi Eso Dike jẹ́ òṣèrékùnrin, olórin, oníṣòwò àti agbẹjọ́rò.[1] Ó gbajúmọ̀ fún ojúṣe rẹ̀ nínú fíìmù Smart Money Woman, níbi tí ó ti ṣe ẹ̀dá-ìtàn Tsola ní ọdún (2020),[2][3][4][5][6]

Eso Dike
Eso at a movie premiere.
Ọjọ́ìbíOkolocha Esowese Dike
Benin City, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́
  • Actor
  • musician
  • television personality
  • lawyer
Ìgbà iṣẹ́2014-present

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Ó lọ sí University of Benin, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin, tó sì gba ìwé-ẹ̀rí LL.B kí ó tó lọ sí Nigerian Law School, ní Abuja, níbi tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí B.L, tí wọ́n sì pè é sí Nigerian Bar.[7]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Dike rí iṣẹ́ kan gẹ́gẹ́ bíi akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ní Spice TV lẹ́yìn tí ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀-òfin.[8] Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún tí ó ń wá iṣẹ́, ní ọdún 2016 Dike darapọ̀ mọ́ fíìmù orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Tinsel.[9]

Ìgbésí-ayé ara ẹni

àtúnṣe

Eso Dike ń gbé ní Èkó. Ó ní ajá kan tí ó ń sìn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Kobe èyí tí ó máa ń sábà wà pẹ̀lú rẹ̀ lórí ẹ̀rọ ayélujára. Ó fẹ́ràn láti máa gbá bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá.[10]

Àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe
Ọdún Fíìmù Ipa Ọ̀rọ̀
2016 Tinsel
2018 Forbidden Charles
Jenifa's Diary Jeff
2019 Made In Heaven Jay
2020 The Smart Money Woman 'Tsola [11]
Finding Hubby Mr.X Directed by Olufemi Ogunsanwo
2021 Our Best Friend's Wedding Ekeng Web Drama-Series
Ricordi Malik TV Series
Ponzi Sam Directed by Kayode Kasum
Desperate Houseboys Antar Elliot Directed by Sunkanmi Adebayo
Situationship Victor Directed by Akin-Tijani Balogun
Ije John Directed by Nwani Orire
Perfect Neighbour Eric Directed by Tissy Nnachi
Charge And Bail Victory Directed by Uyoyou Adia
Duke and Dami Tesola Directed by Ozioma B. Nwughala
Soole Innocent [12]
Dubara
Miss-Understood Mofe
Parallel Lines Ikechukwu
Unintentional Chris
2022 Chief Daddy 2: Going For Broke Killer Bee [13]
Vindictive
Closure
Detty Thirty Morgan
Blood Sisters Ibrahim [14]
The Wildflower Kayode
Greener Lwan Ezekiel
Glamour Girls Hel's Brother
The Bait
Finding Hubby2 Mr.X
The Knot Richard
The Stand Up Direct by Jide Oyegbile
kith & Kin Eche
Flawsome Godspower [15] TV Series
Crazy Therapy Direct by Jide Oyegbile
Weather For Two Kolade Thompson Directed by Wale Adesanya
Ijakumo: The Born Again Stripper Wale [16]
2023 GRIND Kobe TV Series
To Freedom Kevwe Directed by Biodun Stephen
Love In A Pandemic Tejiri (TJ) Directed by Akay Ilozobhie
Be My Valentine Eyo Directed by Nwani Orire
A Dead Man's Souvenir Directed by Tissy Nnachi
Chaos Calling Detective Remi Directed by Biodun Stephen
The Play Book Directed by Muyiwa Aluko
Now That We Are Married Directed by Lota Chukwu
Direct Message Ade Directed by Jay Franklyn Jituboh
2024 Unknown Soja Abuga Thriller
2024 Cold as Ice Ayodeji Directed by Great Valentine Edochie

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Burnaboy, Kizz Daniel, Tems, other Nigerian artistes dominate Tingo Soundcity MVP Award 2023". Business Day. Business Day. Retrieved 17 February 2023. 
  2. Obioha, Vanessa. "Nollywood Needs More Training Schools, Says Eso Dike". This Day. This Day. https://www.thisdaylive.com/index.php/2021/11/26/nollywood-needs-more-training-schools-says-eso-dike/. 
  3. "NET Honours 2022: Eso Dike, Titi Kuti and more Nominated for First-Ever Breakout Actor of the Year Category". thenet.ng. Net NG. Retrieved 24 June 2022. 
  4. "Watch Eso Dike & Taye Arimoro team up on this Episode of "Ndani TGIF Show"". bellanaija.com. Bella Naija. Retrieved 26 March 2021. 
  5. Shola, Oladotun. "Ijakumo: The born again stripper is another cliche narrative with lacklustre acting, dialogue". premiumtimesng.com. Premium Times. Retrieved 6 March 2023. 
  6. "Nigeria’s Box Office Generated N6.94bn Revenue in 2022". thisdaylive.com. This Day. 
  7. "You can’t avoid African content – Eso Dike". sundewsonline.com. The Sun. Retrieved 24 November 2021. 
  8. "10 Things You Don’t Already Know About Actor, Eso Okolocha". thenet.ng. The Net NG. Retrieved 22 July 2019. 
  9. "Top 15 Nigerian Actors to Watch Out For in 2021". thenet.ng. The Net NG. Retrieved 21 January 2021. 
  10. Mofijesusewa, Samuel. "10 things you don't know about actor, Eso Dike". thenet.ng. The Net. Retrieved 22 July 2019. 
  11. "The Cast of Smart Money Woman Reveal their Money Habits & Dish on Working on the TV Series". twmagazine.net. TW Magazine. Retrieved 3 February 2021. 
  12. onu, Stephen. "Movie Review: ‘Soole’ is an ambitious roller coaster movie that is easily forgotten". premiumtimesng.com. Premium Times. Retrieved 22 January 2022. 
  13. "CHIEF DADDY 2 REVIEW: NETFLIX’S SEQUEL IS A BAD START TO AN INITIALLY PROMISING YEAR". afrocritik.com. Afrocritik. Retrieved 5 January 2022. 
  14. "Promising Actors To Watch Out For In 2023". New Telegram. https://www.newtelegraphng.com/promising-actors-to-watch-out-for-in-2023/. 
  15. ""FLAWSOME" REVIEW: ONCE AGAIN, NOLLYWOOD WOMEN AREN’T INDEPENDENT OF MASCULINE CONVENTION". afrocritik.com. Afrocritik. 
  16. Ajose, Kehinde. "How I was lifted with crane on movie set — Eso Dike". Punch. https://punchng.com/how-i-was-lifted-with-crane-on-movie-set-eso-dike/.