Estelle Parsons ni a bini óṣu November, ọdun 1927 to jẹ óṣèrè lóbinrin, ólórin ati oludari ti stage[1].

Estelle Parsons
Estelle Parsons ní ìfẹ ará Amẹrika odún 1973
Ọjọ́ìbíEstelle Margaret Parsons
Oṣù Kọkànlá 20, 1927 (1927-11-20) (ọmọ ọdún 96)
Lynn, Massachusetts, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaConnecticut College
Iṣẹ́
  • Actress
  • singer
  • stage director
Ìgbà iṣẹ́1956–present
Olólùfẹ́Àdàkọ:Married
Peter Zimroth
(m. 1983; died 2021)
Àwọn ọmọ3

Igbesi Ayè Àrabinrin naa àtúnṣe

Estelle ni a bisi ilè iwósan ti Lynn[2]. Iya óṣèrè lóbinrin naa Elinor Ingeborg ti a bini ilẹ sweden ati baba rẹ Eben Parsons to wa lati iran èdè gẹẹsi[3][4].

Parsons fẹ ólukọ iwe Richard Gehman ni ọdun 1953 ti wọn si bi ibeji lóbinrin Abbie (Olúkaroyin) ati Martha Gehman (Óṣèrè lóbinrin). Tọkọ Taya naa pinya ni ọdun 1958. Ni óṣu january, ọdun 1983, Estelle fẹ Peter Zimroth ti wọn si gba ọmọ ọkunrin kan tọ torukọ rẹn jẹ Abraham. Zimroth ku ni ọjọ kẹjọ óṣu November ni ọdun 2021[5][6].

Ẹkọ àtúnṣe

Óṣèrè lóbirnin naa lọsi ilè iwè ti Oak Grove fun awọn óbinrin ni Maine. Estelle naa jade lati collegi ti Connecticut ni ọdun 1949 lẹyin naa lo lọsi ilè iwè giga ti Boston lati kẹẹkọ lóri Amofin[7][8][9].

Ami Ẹyẹ at Idanilọla àtúnṣe

Estelle gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo ti wọn tun yan fun Ami Ẹyẹ Tony lẹ́ẹmẹrin. Ni ọdun 2004, óṣèrè lóbinrin naa ni wọn gba si Theatre Hall ti fame ti ilẹ America[10][11][12][13].

Itokasi àtúnṣe