Etikun ti Oko Ẹru ti iwọ oorun ilẹ Afrika

.

A 1729 map showing the Slave Coast
The Slave Coast is still marked on this c. 1914 map by John Bartholomew & Co. of Edinburgh
Major slave trading regions of Africa, 15th–19th centuries

Etikun Oko Ẹru yi jẹ oruko Adayeba ti a ti lo tẹ̀lẹri fun apa Etikun iwọ oorun ni Agbegbe Bight ti Biafra ati Bight ti Benin to wa ni arin odo Volta ati lagoon ti eko.Órukọ yi ni a yọ latari itan agbegbe naa gẹgẹbi ọna kan gbogi ti awọn ẹya Afrika ma nko lẹru ni owo oko ẹru ti Atlantic lati century mẹrin dinlogun lọsi century ti ọkan dinlogun.

Itan àtúnṣe

Ipa awọn eniyan àtúnṣe

Itọkasi àtúnṣe