Etso Ugbodaga-Ngu
Etso Clara Ugbodaga-Ngu tí a tún mọ̀ sí Ugbodaga-Ngu, fìgbà kan jẹ́ oníṣẹ́-ọnà ọmọ-orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọdún 1921 ní Kano, ní ipinle Kano ni wọ́n bi sí, ó si fi ipa rere sí ọ̀rọ̀ òṣèlú àti àṣà ní ilẹ̀ Nàìjíríà.[1][2] Iṣẹ́-ọnà rẹ̀ máa ń fi okùn hàn. Lára àwon iṣé rẹ̀ ni "Market Women" tí ọdún (1961).
Etso Ugbodaga-Ngu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Etso Clara Ugbodaga-Ngu Àdàkọ:Birth year Kano |
Aláìsí | 1996 (ọmọ ọdún 74–75) |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Ẹ̀kọ́ | Art teacher's diploma, National Diploma in Design |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of London 55, Chelsea School of Art, London, 1954 |
Iṣẹ́ | Artist |
Iṣẹ́ rẹ̀, ìyẹn "Dancers" ni Elbert G. Mathews, tó jẹ́ aṣojú ilẹ̀ U.S. ní Nàìjíríà gbà. Ugbodaga-Ngu ti di ọ̀pọ̀lọpọl ipò mú, ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí akékọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga tó sì tú ní studio rẹ̀. Ó tún ṣịṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i olùdámọ̀ràn ìlú lásìkò FESTAC ní ọdún 1975, ó sì padà di olùkọ́ ní University of Benin.[3][4][5][6]
Ugbodaga-Ngu ṣaláìsí ní ọdún1996.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Clara Ugbodaga-Ngu, Abstract (1960)". University of Birmingham (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-04.
- ↑ Babah, Chinedu (2017-02-03). "NGU Etso Ugbodaga". Biographical Legacy and Research Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-04.
- ↑ James, Sule Ameh (2023-07-26). "Clara Etso Ugbodaga-Ngu's Many Roles in Nigeria's Modernist Art Scene". post (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-04.
- ↑ "Bonhams : Clara Etso Ugbodaga-Ngu (Nigerian, 1921-1996) Dancers". www.bonhams.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-04.
- ↑ "Rare work by the African artist Clara Etso Ugodaga-Ngu comes to Bonhams". South African Art Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-24. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ "Artwork by Clara Etso Ugbodaga-Ngu, Dancers, Made of oil on board in 2023 | Dancer, Snapshots, Sale artwork". Pinterest (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-04.