Etta James (oruko abiso Jamesetta Hawkins, Oṣù Kínní 25, 1938 - Oṣù Kínní 20, 2012) je akorin blues, soul, R&B, rock & roll, gospel ati jazz ara Amerika. Eni to bere ise orin kiko larin ewadun 1950, o gbajumo pelu orin bi "Dance With Me, Henry", "At Last", "Tell Mama", ati "I'd Rather Go Blind", awon eyi to ko fun ra re[1]. O koju orisirisi isoro, larin eyi ti se lilo ogun oloro, ko to tun gbe awo rin miran jade ni opin ewadun 1980 pelu awo orin "The seven year Itch".[2]

Etta James
James ninu ọdún 2006 in Lansing, Michigan
James ninu ọdún 2006 in Lansing, Michigan
Background information
Orúkọ àbísọJamesetta Hawkins
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiMiss Peaches,
Íyálàyà R&B
Ọjọ́ìbí(1938-01-25)Oṣù Kínní 25, 1938
Los Angeles, California, U.S.
AláìsíJanuary 20, 2012(2012-01-20) (ọmọ ọdún 73)
Riverside, California, U.S.
Irú orinBlues, R&B, rock and roll, jazz, soul, gospel
Occupation(s)Singer
InstrumentsVocals, guitar
Years active1954–2012
LabelsModern, Chess/MCA Records, Argo, Crown, Cadet, Island/PolyGram Records, Private Music/RCA, RCA Victor Records, Elektra, Virgin/EMI Records, Verve Forecast/Universal Records
Associated actsHarvey Fuqua, Johnny Otis, Sugar Pie DeSanto

Won gba pe o se japo orin rhythm and blues ati rock and roll, be sini o gba Ebun Grammy ni emefa ati Ebun Orin Blues ni eme 17. Won fun ni eye fifi si Rock and Roll Hall of Fame ni 1993, si Blues Hall of Fame ni 2001, ati si Grammy Hall of Fame ni 1999 ati 2000.[3] Iwe iroyin olosoosu Rolling Stone fun ni ipo 22 ninu atojo awon akorin 100 to se pataki julo lailai ati ipo 62 ninu atojo awon onisona 100 to se pataki julo.[4]



Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe