Fásitì Anchor
Ifáfitì Anchor jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì tí aládàáni tí ó jẹ́ ti ìjọ Deeper Christian Life Ministry. Ilé-ẹ̀kọ́ náà wà ní agbègbè kan ní ìlú Ayọ̀bọ́, Ìpájà ní Ìpínlẹ̀ Èkó,ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Anchor University | |
---|---|
Anchor University .jpg Anchor University | |
Motto | Character, Competence, Courage |
Established | September 2014 |
Type | Private |
Chancellor | William Kumuyi |
Vice-Chancellor | Afolayan Joseph Olasehinde [1][2] |
Location | Ayobo-Ipaja, Lagos State, Nigeria |
Website | aul.edu.ng |
Àwọn Ìtọ́kasí=
àtúnṣe- ↑ "Anchor VC calls for change in societal values". Punch Newspaper.
- ↑ "'Anchor University Vice Chancellor's Welcome Address'". Anchor University. Archived from the original on 2019-12-14. Retrieved 2019-12-14.