Fásitì Odùduwà jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ àdáni tí wọ̀n dá sílẹ̀ ní ọdún 2009. Iké-ẹ̀kọ́ náà wà ní Ilé-Ifẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun. Àwọn olùgbé Ilé-Ifẹ̀ tó iye bí ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọọ́ta, ọgọ́rùún méjì ólé mọ́kàndínláàdọ́ta àti àti mọ́kàndínlọ́gọ́eùún ènìyàn (50,000-249,999). Àjọ (NUC) tí ó ń rí sí ìgbòkè-gbodò ìdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ fásitì nílẹ̀ Nàìjíríà fòntẹ̀ má báṣẹ́ rẹ lọ oẹ̀lú ẹ̀rí tó yanarantí tí wọ́n sì to ilé-ẹ̀kọ́ náà sí ipò kẹrìnlélọ́gọ́rùún (104) láàrín àwọn ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ikẹ̀ Nàìjíríà, nígbà tí ó wà ní ipò ẹgbẹ̀rún kan ólé ọgọ́rùn mẹ́fà àti mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n (10617) ní àwùjọ ilé-ẹ̀kọ́ àgbáyé. Fáfitì Odùduwà ń kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọn ní ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ jákè-jádò àgbọ́ọ̀n-gbẹ ìmọ̀ lóeíṣiríṣi.Oduduwa.

Oduduwa University
OUI
MottoLearning for human development
Established2009
TypePrivate
ChancellorDr. Rahmon Adedoyin
Vice-ChancellorProf. Chibuzo Nnate Nwoke
LocationIpetumodu, Osun State, Nigeria
CampusIpetumodu
Websitehttp://www.oduduwauniversity.edu.ng/

Fásitì Odùduwà fìdí kalẹ̀ sí ìlú Ìpetumodù, Ilé-Ifẹ̀, ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.[1] Wọ́n forí ilé-èkọ́ náà sọ orí baba ńlá àwọn Yorùbá tí ó ń jẹ́ Odùduwà.

Àwọn ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ ibẹ̀ àtúnṣe

Iké-ẹ̀kọ́ náà ni ó ní àwọn ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ wọ̀nyí:

  • College of Management and Social Sciences (CMSS)
  • College of Natural and Applied Sciences (CNAS)
  • College of Environmental Design and Management (CEDM)
  • College of Engineering and Technology (CET)[2]

Ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ ìmọ̀ àwùjọ, ìṣúná àti ìdókòwò (College of Management and Social Sciences (CMSS) ) àtúnṣe

Ètò ẹ̀kọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́-gboyè àkọ́kọ́ (bachelor's degree) ni wọ́n ṣe lọ́wọ́ ní abala ẹ̀ka ètọ́ ẹ̀kọ́ yí.

  • Business Administration
  • Mass Communication & Media Technology
  • Economics
  • Banking & Finance
  • Accounting
  • Public Administration
  • Political Science
  • International Relations.

Ẹ̀ka ẹtò ẹ̀kọ̀ Natural àti Applied Sciences (CNAS) àtúnṣe

Ètò ẹ̀kọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́-gboyè àkọ́kọ́ (bachelor's degree) ni wọ́n ṣe lọ́wọ́ ní abala ẹ̀ka ètọ́ ẹ̀kọ́ yí.

  • Mathematics/Statistics
  • Mathematics/Computer Science
  • Computer Science
  • Physics (Electronics)
  • Chemistry
  • Biochemistry
  • Microbiology/Pre-medicine
  • Industrial Chemistry

Ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ Environmental Design àti Management (CEDM) àtúnṣe

  • Architecture
  • Estate Management
  • Quantity Surveying

Ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ Ìmọ̀-Ẹ̀rọ (CET) àtúnṣe

  • Computer Engineering
  • Electronic/Electrical Engineering

Combination is available with Computer Science

Àwọn ibùdó ìwádìí àtúnṣe

Àwọn wọ̀nyí jẹ́ ibùdó ìwádìí ìmọ̀ nílé-ẹ̀kọ́ náà:

  • Centre for Information and Communications Technology (CICT)
  • Centre for Entrepreneurial and Vocational Training (CEV)
  • Centre for Professional Studies (CPS)
  • Centre for Cultural Studies (CCS)
  • Centre for Foundation and Extra-moral Studies (CFES)
  • Centre for International Studies/Exchange Programmes
  • Centre for Communication and Leadership Training (CCL)

Gbogbo àwọn akẹ́kọ̀ọ́ iké-ẹ̀kọ́ yí láti gba agbònrin ICT àti ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìmọ̀ iṣẹ́ ọwọ́ (TCEVT) kọjá kí wọ́n tó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ́kọ́.[3]

Àwọn ìtọ́ka sí àtúnṣe

  1. "Oduduwa University". Ranking & Review. 2019-05-08. Retrieved 2019-06-02. 
  2. Ibenegbu, George (2018-05-29). "Can you afford Oduduwa school fees?". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2019-06-02. 
  3. ":: ODUDUWA UNIVERSITY ::". :: ODUDUWA UNIVERSITY ::. Retrieved 2019-06-02. 

Àwọn ìjásóde àtúnṣe