Ipetumodu jẹ́ ìlú ńlá kan ní ilẹ̀ Yorùbá ní apá Ìwọ-oòrùn Gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà, ó sì jẹ́ ìlú pàtàkì kan ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun tí ó sì jẹ́ olú ìlú Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Ife. Ìlú yìí ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga aládàáni kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Oduduwa University àti ilé-ìwé gírámà márùn-ún, tí ó jẹ́ ti ìjọba àti ilé-ìwé Federal Government Girls' College. Iṣẹ́ ti àwọn ará Ipetumodu máa ń ṣe ni iṣẹ́ àgbẹ̀ àti iṣẹ́ ìkòkò mímọ.

Ipetumodu
Nickname(s): 
Ipetu Alape
Motto(s): 
Center of creativity and honey land
Ipetumodu is located in Nigeria
Ipetumodu
Ipetumodu
Coordinates: 7°30′25.17″N 4°26′40.76″E / 7.5069917°N 4.4446556°E / 7.5069917; 4.4446556Coordinates: 7°30′25.17″N 4°26′40.76″E / 7.5069917°N 4.4446556°E / 7.5069917; 4.4446556
Country Nigeria
StateOsun State
Local Government AreaIfe North
Founded byAkalako
Government
 • TypeKingdom
 • ApetumoduOba Joseph Olugbenga Oloyede Latimogun I
Elevation
239.537311 m (785.883566 ft)
Population
 (2013 Estimation)
 • Total135,000
 • Density144/km2 (370/sq mi)
Time zoneUTC+1 (WAT)
Websiteipetumodudevelopmentforum.ng
Àwòrán kájúkáko Ipetumodu

Ìtàn ìlú ipetumodu

àtúnṣe

Àwọn akọni tó kọ́wọ̀ọ́rìn bíi Orunmila àti Obatala[1] ló tẹ ìlú náà dó láti àringbùngùn ayé. Ìtàn fi yé wa pé wọ́n jagun gba Ilé-Ifẹ̀,[2] tí wọ́n sì lé àwọn ẹ̀yà Igbo jáde kúrò ní Ilé-Ifẹ̀. Akalako tí ń ṣe ọmọ Obatala, tí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ Adetinuwe tí í ṣe ọmọbìnrin Odùduwà ní Ipetumodu àkọ́kọ́. Ó máa ń pa ẹ̀tù bọ Odù Ifá rẹ̀, ibẹ̀ sì ni orúkọ ìlú yìí ti jẹ wá, ìyẹn Ipetumodu.[3][4][5]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "His Imperial Majesty, Alayeluwa Oba Okunade Sijuwade, Olubuse ll- The Ooni of Ife". Theooni.org. Archived from the original on 2014-06-23. Retrieved 2014-08-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "t4di ...welcome to Nigeria". Tourism.powef.org. Archived from the original on 2014-08-26. Retrieved 2014-08-25. 
  3. "The Nation April 1, 2012 by The Nation". ISSUU. 2012-04-01. Retrieved 2014-08-25. 
  4. "Ipetumodu Sets To Raise N500m For Community Development". Osun Defender. 2012-10-31. Archived from the original on 2014-08-26. Retrieved 2014-08-25. 
  5. Approved Estimate of Ife North Local Government, Ipetumodu, Osun State, Nigeria - Ife North Local Government Area (Nigeria) - Google Books. 2011-07-14. https://books.google.com/books?id=f-klAQAAMAAJ. Retrieved 2014-08-25.