Olúfẹ́mi "Fémi" Pedro (tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kìnínní ọdún 1955 ni Ilu Eko)  tí fìgbà kan jẹ́ Igbákejì Gómìnà ti Ìpínlẹ̀ Èkó, ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà latí ọdún 2003 títí di ọdún 2007. Kí a tó dìbò yàn án pẹ̀lú Bọ́lá Tinúbú, ó jẹ́ ó̀gá àgbà ilé-iṣẹ́ àti ọ̀kan lára àwọn òlùdásílẹ̀ ilé-iṣé First Atlantic Bank, tí a mọ̀ sí FinBank báyìí

Femi Pedro
Ọjọ́ìbíOlufemi Olusegun Pedro
(1955-01-29)29 Oṣù Kínní 1955
Lagos Island, Lagos State
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Wisconsin
Wichita State University
Iṣẹ́Politician
Banker
Ìgbà iṣẹ́2003–present
Political partyAll Progressives Congress
Olólùfẹ́Hon. Justice Jumoke Pedro

Ní báyìí, Fẹ́mi Pedro jẹ́ Alága fún ilé-iṣẹ́ Ìjọba tó ń rí sí ìdàgbàsókè okowò pẹ́pẹ̀pẹ́ (Small and Medium Enterprise Development Agency of Nigeria, SMEDAN), ó sìn tún jẹ́ Alága àkọ́kọ́ fún Ẹ̀ka Ilé-iṣẹ́ ìkówójọ fún Eré-Ìdárayá ní Ìpínlẹ̀ Èkó (Lagos State Sports Trust Fund.)

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe