Fade Ogunro
Fade Ogunro Jẹ́ agbóhùn sáfẹfẹ́ ilé isé ìròyìn àti amóhùnmáwòrán, olóòtú fíìmù àti aràsọ/amúnidára. Òun ni olùdásílẹ̀ àti olùdarí ilé isé e Bookings Africa, ilé isé kan fún pèsè kárdì fún lílọ ẹ̀rọ ayélujára ní ilẹ̀ Áfríkà. Ó jẹ́ ọmọbíbí ìpínlẹ̀ Ekiti ní apá ilà-oòrùn orílẹ́-èdè Nàìjíríà. Ó ń sọ èdè Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Faransé àti Èdè Spéìn.[1][2]