Fati Abubakar
Oluyaworan Naijiria
Fati Abubakar jẹ́ gbajúmọ̀ oníròyìn aláwòrán àti afohùn-fawòrán ṣàgbékalẹ̀ ètò. Ó jẹ́ ọmọbìnrin ọmọ bíbí Maiduguri, ní Ìpínlẹ̀ Borno orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ni bí ti o gbajúmọ̀ dé, ìwé-ìròyìn The New York Times, CNN Africa, BBC àti Voice of America ṣe àtẹ̀jádé iṣẹ́ rẹ̀. [1]
Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeFati jẹ ògidì ọmọ bíbí ìlú Maiduguri, ní Ìpínlẹ̀ Borno lórílẹ̀-èdè Nigeria.[2][3]
Gbajúmọ̀ àti ògidì nínú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ní àwọn gbankọ̀gbì àwọn ìwé ìròyìn òkè-òkun The New York Times, CNN Africa, BBC àti Voice of America tí fìgbà kan tẹ̀ jáde nínú ìwé ìròyìn wọn.[1] Ó ṣiṣẹ́ láti ṣe àgbékalè lórí làálàá àti ìṣòro tí ó dojú kọ Ìpínlẹ̀ Borno, pàápàá jù lọ, wàhálà àwọn agbésùnmọ̀mí Boko Haram. Ó ṣe iṣẹ́ kan tí ó pè ní Bits of Borno.[1][4][5]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 "LagosPhoto | International art festival of photography in Nigeria". LagosPhoto. Retrieved 20 April 2019.
- ↑ "Fati Abubakar". africasacountry.com. Retrieved 20 April 2019.
- ↑ "'She has been our family's lifeline'". Nursing Standard 31 (9): 65. 26 October 2016. doi:10.7748/ns.31.9.65.s48. ISSN 0029-6570. PMID 27787168.
- ↑ "About". Bits of Borno. Archived from the original on 11 November 2020. Retrieved 20 April 2019.
- ↑ "Women in war zones: Shooting the frontline when you're not a middle class man". Huck Magazine. 19 October 2018. Retrieved 20 April 2019.