Fati Lami Abubakar
Fati Lami Abubakar tí wọ́n bí lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1951 (12 April 1951) jẹ́ Adájọ́ àgbà Ìpínlẹ̀ Niger, Obìnrin àkọ́kọ́ fún Nàìjíríà àti Aya Ààrẹ-àná, Abdulsalami Abubakar lọ́dún 1998 sí 1999. Ó di Adájọ́ àgbà ní Ìpínlẹ̀ Niger lọ́dún 2013 sí 2016.
Hon Fatima Lami Abubakar | |
---|---|
Adájọ́ àgbà fún Ìpínlẹ̀ Niger | |
In office March 2013 – April 2016 | |
Asíwájú | Hon. Justice Jibrin Ndajiwo |
Obìnrin àkọ́kọ́ fún Nàìjíríà àti Aya Ààrẹ-àná lọ́dún 1998 sí 1999 | |
In office June 1998 – May 1999 | |
Ààrẹ | Abdulsalami Abubakar |
Asíwájú | Maryam Abacha |
Arọ́pò | Stella Obasanjo |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Fatima Lami 12 Oṣù Kẹrin 1951 Minna, Nigeria |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Abdulsalami Abubakar |
Àwọn ọmọ | Six |
Ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Fati lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1951 ní ìlú Minna, ní [[Ìpínlẹ̀ Niger] [lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ó kàwé ni Queen Elizabeth School ní [[Ilorin], ní Ìpínlẹ̀ Kwara.[1] Bẹ́ẹ̀ náà, ó kàwé ní Federal Government College, ní Ìpínlẹ̀ Sokoto, àti ní Obafemi Awolowo University, Ilé Ifẹ̀, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òfin, bẹ́ẹ̀ náà ló kàwé gboyè ọ̀mọ̀wẹ́ nínú ìmọ̀ Philosophy.[2] Bákan náà, Fati kàwé gboyè ní 'Nigeria Law School'.[1]
Ìgbésí ayé rẹ̀ lọ́tọ̀
àtúnṣeFati Lami fẹ́ Àárẹ̀ àná, Abdulsalami Abubakar, wọn sìn bí ọmọ mẹ́fà fún ara wọn.[3]
Ayé rẹ̀
àtúnṣeAbubakar ti fẹ́ Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí, Abdulsalami Abubakar, ẹni tí ó bí ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú. [4]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Yawa-Siraja, Uthman (19 April 2016). "Justice Fati Abubakar, exit of an incorruptible judge". Newsline (Niger Printing and Publishing Company). Archived from the original on 11 November 2020. https://web.archive.org/web/20201111140844/http://www.newsline.org.ng/2016/04/19/justice-fati-abubakar-exit-of-an-incorruptible-judge/. Retrieved 3 December 2017.
- ↑ "Hon. Justice Fati Lami Abubakar". Women's Rights Advancement and Protection Alternative. Retrieved 3 December 2017.
- ↑ Ukwu, Jerrywright. "Justice Fati Abubakar retires as Niger state chief judge". Naij. https://www.naija.ng/800664-former-nigerian-first-lady-retires-chief-judge.html. Retrieved 4 December 2017.
- ↑ Ukwu, Jerrywright. "Justice Fati Abubakar retires as Niger state chief judge". Naij. https://www.naija.ng/800664-former-nigerian-first-lady-retires-chief-judge.html.