Stella Obasanjo
Stella Obasanjo (14 November 1945 – 23 October 2005) ni Iyaafin Akoko ile Naijiria lati 1999 titi di ojo iku re ni 23 osu kewa, 2005. Ohun ni iyawo aare totikoja Olusegun Obasanjo.
Stella Obasanjo | |
---|---|
Ìyáàfin Àkọ́kọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà | |
In office 29 May, 1999 – 23 October, 2005 | |
Asíwájú | Fati Lami Abubakar |
Arọ́pò | Turai Yar'Adua |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 14 November 1945 Esan West, Edo State, Nigeria |
Aláìsí | 23 October 2005 Puerto Banús, Marbella, Spain | (ọmọ ọdún 59)
(Àwọn) olólùfẹ́ | Olusegun Obasanjo |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |