Fatima Muhammad Lolo
Hajiya Fatima Lolo (MON), (a bí Fatima Muhammad Kolo ní Pategi, Royal Niger Company ; ọjọ́ kọkàndínlógún, oṣù kìíní ọdún1891 – ọjọ́mẹ́ẹ̀dógún oṣù karùn-ún ọdún 1997) ó jẹ́ , akọrin, olùkọ̀wé orin, àti onímọ́ nípa ìtàn. [1]
Hajiya Fatima Lolo | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Fatima Muhammadu Kolo |
Ọjọ́ìbí | Pategi, Royal Niger Company, Colonial Nigeria | 19 Oṣù Kínní 1891
Ìgbà Èwe
àtúnṣeLolo ṣe ìgbéyàwó lẹ́ẹmejì, èyí tí kò rọ́mọ bí nínú ìgbéyàwó méjèèjì. Ó ṣe aṣojú àwọn Ìjọba Nupe ní onírúurú àjọ̀dún àti ayẹyẹ .Ṣáájú kí ó tó di olókìkì. Wọ́n mọ̀ọ́n-ọ́n nípa ṣe orin tí ó máa ń kọ fún àwọn àgbẹ̀ àti àwọn ọdẹ ní àkókò tí ó ń Jóò pẹ̀lú àbọ̀ pẹlẹbẹ lọ́wọ́ rẹ̀. Lẹ́hìn ìgbà náà, wọ́n tọ́ka rẹ̀ sí Sagi Ningbazi (Olorì àwọn Ọ̀nkọrin) ní ède Nupe. Shehu Shagari ni o fun un ni MON ti Aṣẹ ti Niger. [2]