Faure Essozimna Gnassingbé (ojoibi June 6, 1966[2]) ni Aare ile Togo lati May 4, 2005. O je omo Aare Gnassingbé Eyadéma, baba re yan si ibise ijoba gege bi Alakoso oro Irinse, Alumoni, Ifiweranse ati Ibanisorolookan lati 2003 to 2005. Leyin iku Eyadéma ni 5 February, 2005 Gnassingbé di Aare. Oruko iya re ni Sena Sabine Mensah. o ka ile iwe giga ni lome, o kawe gboye ninu imo eto isuna okowo ni Sorbonne, Paris. O te siwaju lati gba masitasi ni George Washinton Unifasiti ni Amerika.

Faure Essozimna Gnassingbé
Faure Gnassingbé 29112006.jpg
President of Togo
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
4 May 2005
Alákóso Àgbà Koffi Sama
Edem Kodjo
Yawovi Agboyibo
Komlan Mally
Gilbert Houngbo[1]
Asíwájú Bonfoh Abbass (Acting)
Lórí àga
5 February 2005 – 25 February 2005
Alákóso Àgbà Koffi Sama
Asíwájú Gnassingbé Eyadéma
Arọ́pò Bonfoh Abbass (Acting)
Personal details
Ọjọ́ìbí 6 Oṣù Kẹfà 1966 (1966-06-06) (ọmọ ọdún 53)
Afagnan, Togo
Ẹgbẹ́ olóṣèlu RPT


ItokasiÀtúnṣe