Gilbert Fossoun Houngbo (ojoibi 4 February 1961[1]) je oloselu omo ile Togo to ti je Alakoso Agba ile Togo lati 8 September 2008.[2]

Gilbert Fossoun Houngbo
Prime Minister of Togo
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
8 September 2008
ÀàrẹFaure Gnassingbé
AsíwájúKomlan Mally
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí4 February 1961
Alma materUniversity of Lomé
Gilbert Houngbo (2010)

Eko àtúnṣe

Houngbo gba iwe eri giga ninu ibojuto isowo lati University of Lomé ni Togo, bakanna o tun gba iwe eri ninu isesiro ati inawo lati Université du Québec à Trois-Rivières ni Kanada. O je omo egbe Canadian Institute of Chartered Accountants.[3]

Ni Oṣu Kini Ọdun 2022, Gilbert Houngbo jẹ Alaga tuntun ti Igbimọ Alakoso Ohun elo Adayeba (NRGI).



Itokasi àtúnṣe

  1. "Démission du Premier ministre", Republicoftogo.com, 5 May 2010 (Faransé).
  2. "Reprise de la coopération et gestion de crise"[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], Republicoftogo.com, 8 September 2008 (Faransé).
  3. "Gilbert Fossoun Houngbo, "l’oiseau rare""[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], Republicoftogo.com, 9 September 2008 (Faransé).