Fay Bainter
Fay Okell Bainter (December 7, 1893 – April 16, 1968) jẹ́ òṣèré orí ìtàgè ni orílé èdè Améríkà.[2] Óò gbà àmi ẹ̀yẹ ni Akádẹ́mì fún ẹni tí ó ń ṣe amúgbálẹ́gbẹ́ fún Olu òṣèré inú eré tí àkọlé rẹ ń ni Jezebel ní ọdún 1938, ó sí gbà Àmi ẹyẹ Irawọ ní Hollywood Walk of Fame ní ọdún na. Fay Bainter jẹ́ òṣèrée tó gba Ẹ̀bùn Akádẹ́mì gẹgẹ bí obìnrin Òṣèré Kejì tí ó Didarajulo.
Fay Bainter | |
---|---|
Bainter in 1950 | |
Ọjọ́ìbí | Fay Okell Bainter Oṣù Kejìlá 7, 1893 Los Angeles, California, U.S.[1] |
Aláìsí | April 16, 1968 Los Angeles, California, U.S. | (ọmọ ọdún 74)
Resting place | Arlington National Cemetery |
Iṣẹ́ | Actress, Singer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1910–1961 |
Olólùfẹ́ | Reginald Venable (m. 1921; his death 1964) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé
àtúnṣeWọ́n bí Sí Los Angeles ní California, ó sí jẹ́ ọmọ bíbí Charles F. Bainter àti Mary Okell. Ní ọdún 1910, o jẹ́ òṣèré orí ìtàgè tí o má ń lọ káàkàkiri. Ní ọdún 1908 ni ó kọ́kọ́ ṣe afihan ará rẹ nínú eré ori ìtàgè tí àkọlé rẹ ń jẹ́ The county Chairman ní orí ìtàgè kàn ní Morosco ni Burbank, ní ìlú California, lẹyìn èyí ni ó jáde sí Broadway tí o kópa nínú eré kàn tí àkọlé rẹ ń jẹ́ "The Rose Of Panama" tí ọ jẹ Celine Marinter ní ọdún 1912. Lẹyìn ìgbà yìí óò ti ṣe oríṣi àwọn eré ori ìtàgè lọ́pọ̀ yanturu ní ìlú New York, àwọn àkọlé eré náà sì ni "East Is West, The he Willow Tree, and Dodsworth (play). Ní ọdún 1926, ó wà nínú eré kàn tí ó ṣe Waiter Abel tí àkọlé eré náà sì ń jẹ Enemy èyí tí ó jẹ́ eré Broadway kàn tí Channing Pollock kọ.
Ìgbé ayé
àtúnṣeFay Bainter àti Reginald Venable ṣe ìgbéyàwó ní oṣù kẹfà ọdún 1921 ni Riverside ní California.[3] Àwọn méjèèjì sí ní ọmọ ọkùnrin kàn tí wón sọ ní Reginald Venable Jr. ní (1926-1974) tí ọmọ náà sì jẹ́ òṣèré Bainter jẹ́ ẹgbọn fún òṣeré tí amò sí Dorothy Burgess Reginald Venable jẹ́ Agbófínro fún orílé èdè Améríkà. Wọ́n sìn Fay àti ọkọ rẹ sí itẹ́ òkú Arlington National Cemetery.[4]
Ìgbé ayé
àtúnṣeFay Bainter àti Reginald Venable ṣe ìgbéyàwó ní oṣù kẹfà ọdún 1921 ni Riverside ní California.[3] Àwọn méjèèjì sí ní ọmọ ọkùnrin kàn tí wón sọ ní Reginald Venable Jr. ní (1926-1974) tí ọmọ náà sì jẹ́ òṣèré Bainter jẹ́ ẹgbọn fún òṣeré tí amò sí Dorothy Burgess Reginald Venable jẹ́ Agbófínro fún orílé èdè Améríkà. Wọ́n sìn Fay àti ọkọ rẹ sí itẹ́ òkú Arlington National Cemetery.[5]
Àwọn eré rẹ̀
àtúnṣeYear | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
1934 | This Side of Heaven | Francene Turner | |
1937 | Quality Street | Susan Throssel | |
1937 | The Soldier and the Lady | Strogoff's Mother | |
1937 | Make Way for Tomorrow | Anita Cooper | |
1938 | White Banners | Hannah Parmalee | Nominated – Academy Award for Best Actress |
1938 | Jezebel | Aunt Belle Massey | Academy Award for Best Supporting Actress |
1938 | Mother Carey's Chickens | Mrs. Margaret Carey | |
1938 | The Arkansas Traveler | Mrs. Martha Allen | |
1938 | The Shining Hour | Hannah Linden | |
1939 | Yes, My Darling Daughter | Ann "Annie" Murray | |
1939 | The Lady and the Mob | Hattie Leonard | |
1939 | Daughters Courageous | Nancy "Nan" Masters | |
1939 | Our Neighbors – The Carters | Ellen Carter | |
1940 | Young Tom Edison | Mrs. Samuel (Nancy) Edison | |
1940 | Our Town | Mrs. Julia Hersey Gibbs | |
1940 | A Bill of Divorcement | Margaret "Meg" Fairfield | |
1940 | Maryland | Charlotte Danfield | |
1941 | Babes on Broadway | Miss "Jonesy" Jones | |
1942 | Woman of the Year | Ellen Whitcomb | |
1942 | The War Against Mrs. Hadley | Stella Hadley | |
1942 | Journey for Margaret | Trudy Strauss | |
1942 | Mrs. Wiggs of the Cabbage Patch | Mrs. Elvira Wiggs | |
1943 | The Human Comedy | Mrs. Macauley | |
1943 | Presenting Lily Mars | Mrs. Thornway | |
1943 | Salute to the Marines | Jennie Bailey | |
1943 | Cry 'Havoc' | Captain Alice Marsh | |
1944 | The Heavenly Body | Margaret Sibyll | |
1944 | Dark Waters | Aunt Emily | |
1944 | Three Is a Family | Frances Whittaker | |
1945 | State Fair | Melissa Frake | |
1946 | The Kid from Brooklyn | Mrs. E. Winthrop LeMoyne | |
1946 | The Virginian | Mrs. Taylor | |
1947 | Deep Valley | Ellie Saul | |
1947 | The Secret Life of Walter Mitty | Mrs. Eunice Mitty | |
1948 | Give My Regards to Broadway | Fay Norwick | |
1948 | June Bride | Paula Winthrop | |
1951 | Close to My Heart | Mrs. Morrow | |
1953 | The President's Lady | Mrs. Donaldson | |
1961 | The Children's Hour | Mrs. Amelia Tilford | Laurel Award for Top Female Supporting Performance (2nd place) Nominated – Academy Award for Best Supporting Actress Nominated – Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture |
Àwọn Àfihàn rè lorí Rẹ́díò
àtúnṣeYear | Program | Episode/source |
---|---|---|
1946 | Suspense | 180/“The Lucky Lady” |
1952 | Theatre Guild on the Air | "The Search"[6] |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Fay Bainter". The Montreal Gazette: p. 35. Apr 18, 1968. https://news.google.com/newspapers?id=oAIuAAAAIBAJ&pg=4447,4238367.
- ↑ Obituary Variety, April 24, 1968.
- ↑ 3.0 3.1 Los Angeles Times, November 24, 1921, "Marriage Of Star Is Declared – Wedding of Fay Bainter and Navy Man Revealed by Mother of Actress", p. 17.
- ↑ Arlington National Cemetery
- ↑ Arlington National Cemetery
- ↑ Kirby, Walter (March 16, 1952). "Better Radio Programs for the Week". The Decatur Daily Review. p. 44. https://www.newspapers.com/clip/2470060/the_decatur_daily_review/.
Fún Àkàsíwaju si
àtúnṣe- Alistair, Rupert (2018). "Fay Bainter". The Name Below the Title : 65 Classic Movie Character Actors from Hollywood's Golden Age (softcover) (First ed.). Great Britain: Independently published. pp. 22–25. ISBN 978-1-7200-3837-5.