Felicity Okpete Ovai (tí a bí ní 1961) jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ(Engineer) àti Ọ̀mọ̀wé láti Degema ti ìpínlè Rivers, Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Rivers State People's Democratic Party, òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí a yàn sípò kọmíṣọ́nà fún iṣẹ́, ó dipò náà mú láàrin ọdun 2003 sí 2006.[2][3]


Felicity Okpete Ovai
Kọmíṣọ́nà fún iṣẹ́ ti ìpínlẹ̀ Riverz
In office
2003–06
GómìnàPeter Odili
AsíwájúDavid Briggs
Arọ́pòJulius Orumbo[1]
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1961 (ọmọ ọdún 62–63)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDP
Alma materRivers State University of Science and Technology
University of Port Harcourt
ProfessionEngineer

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. John Iwori (15 March 2006). "Odili Warns New Appointees On Corruption". Thisday. http://allafrica.com/stories/200504041179.html. Retrieved 19 June 2016. 
  2. Okon Bassey (26 April 2005). "Work Begins On N11.8bn Road Project". Thisday. http://allafrica.com/stories/200504041179.html. Retrieved 19 June 2016. 
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Women