Felipe Calderón
(Àtúnjúwe láti Felipe Calderon)
Felipe de Jesús Calderón Hinojosa (Pípè: [feˈlipe kaldeˈɾon]; ojoibi on August 18, 1962) ni Aare ile Meksiko lowolowo. O bo si ori aga ni December 1, 2006, o si tun je didiboyan fun igba odun mefa lekansi titi de 2012.
Felipe de Jesús Calderón Hinojosa | |
---|---|
Ààrẹ ilẹ̀ Mẹ́ksíkò | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga December 1, 2006 | |
Asíwájú | Vicente Fox |
Secretary of Energy | |
In office September, 2003 – June 1, 2004 | |
Asíwájú | Ernesto Martens |
Arọ́pò | Fernando Elizondo Barragán |
16th President of the National Action Party | |
In office 1996–1999 | |
Asíwájú | Carlos Castillo Peraza |
Arọ́pò | Luis Felipe Bravo Mena |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kẹjọ 1962[1] Morelia, Michoacán, Mexico |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | National Action Party (PAN) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Margarita Zavala |
Alma mater | Escuela Libre de Derecho, Instituto Tecnológico Autónomo de México and Harvard University |
Occupation | Politician |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Felipe Calderón". Encyclopædia Britannica. Encyclopædia Britannica. http://www.britannica.com/eb/article-9437374. Retrieved 2008-06-09.
- ↑ "Catholic family meeting circles wagons around traditional family". AFP. 2009-01-14. Archived from the original on 2009-01-21. Retrieved 2009-06-23.
Mexican President Felipe Calderon, a self-described devout Catholic conscious of the fact that five million women head single-parent households in Mexico, said a compromise was needed.