Fella Makafui
Òṣèrébìnrin ilẹ̀ Ghana
Fella Precious Makafui (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹjọ, ọdún 1995) jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ Ghana àti onínúure ènìyàn.[1][2] Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú fíìmù Yolo.[3][4]
Fella Makafui | |
---|---|
Fella Makafui | |
Ọjọ́ìbí | Fella Precious Makafui 20 Oṣù Kẹjọ 1995 Volta Region, Ghana |
Orílẹ̀-èdè | Ghanaian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Ghanaian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Ghana |
Iṣẹ́ |
|
Olólùfẹ́ | Medikal (m. 2020) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Awards | Golden Most Promising, Golden Movie Awards 2016 |
Ìgbésí ayé ara ẹni àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Fella ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹjọ, ọdún 1995 ní Volta Region, Ghana. Ó parí ètò ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní Kpando Senior High School, ó sì tẹ̀síwájú láti gboyè ẹ̀kọ́ ní University of Ghana.[2]
Ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú olórin tàkasúfẹ̀é kan tí orúkọ rẹ̀ ń jé Medikal, tí wọ́n sì bí ọmọbìnrin kan tí wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Island. Wọ́n ṣe ìkéde ìpínyà wọn ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣụ̀ kẹta ọdún 2024.[5]
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣe- Most Promising Actress of the Year - City People Entertainment Award (2016)
- Golden Most Promising - Golden Movie Awards 2016[6]
Àṣààyan àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣe- Kada River (2018) bíi Nadia
- Sugar (2019) bíi Whitney
- Away Bus (2019) bíi Kiki
- Till Deaf Do Us Part (2023)
- Resonance (2024)
- Fata (2024)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "I love your hard African face – Medikal tells Fella Makafui". www.myjoyonline.com. Retrieved 2019-07-13.
- ↑ 2.0 2.1 Githuri, Job (2018-11-12). "Fella Makafui's life- short facts about her life". Yen.com.gh - Ghana news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-07-11.
- ↑ "Yolo actress Fella Makafui turns a year older". www.ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-07-13.
- ↑ "Fella Makafui disappointed in Tinny for releasing raunchy video". www.ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-07-13.
- ↑ "Rapper Medikal announces separation from Fella Makafui - MyJoyOnline". www.myjoyonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2024-04-01. Retrieved 2024-05-16.
- ↑ Online, Peace FM. "Yolo Star Fella Makafui Wins Two Awards In A Month". www.peacefmonline.com. Archived from the original on 2024-11-13. Retrieved 2019-07-13.