Ferdinand Omurwa

Ferdinand Omanyala Omurwa, (tí a bi ni ọjọ kéji Oṣu Kini ọdun 1996) jẹ́ elere-ije ara fún orílẹ̀-èdè Kenya ti o ṣe amọja ni àwọn ipele 100m àti 200m. o hun naa Lọwọlọwọ l'o jẹ́ olugbasilẹ igbasilẹ Afirika ati ọkunrin 8th ti o yara ju gbogbo akoko ni mita 100 lẹhin tito akoko kan tí 9.77 ni ọjọ 18th Oṣu Kẹsan 2021 ni Ilu Nairobi.

Ferdinand Omanyala Omurwa
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèKenyan
Ọjọ́ìbí2 Oṣù Kínní 1996 (1996-01-02) (ọmọ ọdún 27)
Nairobi, Kenya
Ẹ̀kọ́Friends School Kamusinga
Height1.75 m
Weight83 kg
Sport
Erẹ́ìdárayáSprinting
Event(s)100 metres
Achievements and titles
Personal best(s)

Iṣẹ-ṣiṣeÀtúnṣe

Omurwa gba akọle orilẹ-ede ni 100 m ni ọdun 2019. Omurwa ṣeto igbasilẹ orilẹ-ede ti 10.01 iṣẹju-aaya ni 100 mita ni bibori ipade kan ni Yabatech Sport Complex, Lagos (NGR) ni ọjọ 30 Oṣu Kẹta 2021. Ni Awọn ere Igba ooru 2020 100 mita ipele to kangun si ipari o fi itan titun silẹ ti orilẹ-ede tuntun ni owo aaya 10.00.

Ogun OloroÀtúnṣe

O kuna nigbati won se ayewo Ogun Oloro ti o Lodi si ere idaraya kan ni ọdun 2017 Omurwa gba idaduro oṣu 14 kan. O ṣe ayewo, won si ba Ogun ilera betamethasone, lẹhin ti o gba itọju fun ipalara ẹhin rẹ ti o ni nigbati oun gbaradi.

Igbasilẹ idijeÀtúnṣe

Ni ibẹrẹ ọdun 2016 Ferdinand Omanyala bẹrẹ iṣẹ ere-idaraya rẹ ni Kenya bi onigbawole titun ni University of Nairobi. O ṣe igbesẹ yii lẹhin ti ọrẹ kan ṣe akiyesi iyara rẹ lakoko ti o nṣere rugby. O fi igboya ṣe iyipada lati rugby si ere sisa ati pe lehin osẹ diẹ lẹhin na o sare akoko ti 10.4s ni ipade AK akọkọ rẹ ni Kakamega. Ni ọdun kanna, o gba Ami eyé idanwo Olimpiiki ti orilẹ-ede lori 100m ni akoko aaya10.37s ṣugbọn ko pade boṣewa iyege fun Olimpiiki eyiti o jẹ 10.16s ni akoko yẹn.

Ni ése tó kangun si pari ti 100m awọn ọkunrin ni Olimpiiki Igba ooru 2020 ni Tokyo, Omurwa sare 10.00, eyiti o jẹ 0.04 lẹhin eniti o gba fadaka Fred Kerley ati 0.02 lẹhin eniti to ogba Ami Idẹ Andre De Grasse .

Am anṢaaju ilọsiwaju nla rẹ ni Ilu Nairobi, ere re ti o dara julọ ni 100M jẹ iṣẹju-aaya 9.86 ni Pramtalstadion, Andorf (AUT). Awọn onigbowo osise rẹ jẹ Odibets, ile-iṣẹ kalokalo ere idaraya ni Kenya. [1]

Ni Oṣu Kẹsan ọjọ 18, Ọdun 2021, o sare 9.77 (+1.2 m/s) fun igbasilẹ Afirika tuntun ni Absa Kip Keino Classic Continental Tour ti o waye ni ilu Nairobi, Kenya ti o ww ni ipo keji lẹhin Trayvon Bromell ti Amerika ti o je wipe oun lo lë waju pelu Aaya 9.76 ni odun 2021.

Awọn itọkasiÀtúnṣe

Ita ìjápọÀtúnṣe