Flavia Tumusiime Flavia je osere ati agbalejo ori redio ati tefisonu ti owa lati ilu Ùgándà,[3][4]emcee ati onkowe 30 Days of Flavia.[5]O man se eto ni oganjo owuro lori ikani 91.3 Capital FM redio ni Kampala,[6]o ti seto tele ri ni Morning @ NTV lori NTV Uganda ibiyi na ni o tin se eto gegebi VJ fun Channel O.[7] O ko ipa Kamali Tenywa ninu jara ti Nana Kagga se, ti akori re je Beneath The Lies - The Series lati odun 2014 titi di odun 2016 oti sise pelu eto Guinness Football Challenge.[8][9]

Flavia Tumusiime K
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kejì 1989 (1989-02-11) (ọmọ ọdún 35)
Orílẹ̀-èdèUgandan
Ẹ̀kọ́Kitante Hill Secondary School|Makerere University Business School
Iṣẹ́Osere, agbalejo ori redio ati telifisonu
Ìgbà iṣẹ́2006–titi di isinyi
Gbajúmọ̀ fún
  • 30 Days of Flavia
  • Beneath The Lies - The Series|Beneath The Lies
  • Kiwani: The Movie
Olólùfẹ́
Andrew Kabuura (m. 2019)
[1]
Àwọn ọmọLiam Ashaba Kabuura (son)[2]
WebsiteHomepage

Igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ

àtúnṣe

Won bi Tumusiime ni odun 1989 ni Kampala, o je omo kan soso ti Enoch Tumusiime ati Christine Asiimwe bi, won wa lati ilu Kabale, ni guusu-iwọ-oorun Uganda.[10] O lo si ile eko ibere Theresa Kisubi, lehin wa igbano olosi Kitante Hill Secondary Schoolfun O ati A level e. Olo si ile eko giga Makerere University Business School ni ibiyii ni oti gba oye eko ile iwe giga ninu owo ilu okeere.[11][12]

Tẹlifisiọnu

àtúnṣe

Tumusiime je agbalejo ori telifisonu lati igba ti o wa ni ewe. Lehin igba na o bere ise pelu ile ise telifisonu WBS fun awon ewe, o se eto yi fun odun merin pelu awon ewe miran.[13]Ni odun 2010 ati 2012 o se adari eto K-files. Ni odun 2011 o dari Guinness football challenge. Won gbe sori afefe ni NTV(Uganda) ati ITV ati KTn titi ilu Kenya. In the same period, o se ise vj lori Channel o.[14] O se oludari Big Brother Africa ni odun 2012.[15][16]

Flavia darapomo NTV Uganda gegebi adari iroyin lorin NTV Tonight ni odun 2016. O wa lara awon oludari eto aro kan lori NTV ti o bere ni odun 2018.

Tumusiime se ise gegebi adari eto lori ikani HOT 100 FM ni odun 2006 ki oto wa pada si Capital FM ibi ti owa disinyi.[17][18]

Awon ami eye

àtúnṣe
  • Ami eye fun aworam ati iroyin titi Young Achievers Award
  • Ami eye fadaka fun eto aro ti odara julo ni Radio and TV awards ti odun 2013.[19]
  • Ami eye eni awokose fun awon odo ti Buzz Teeniez Awards odun 2013.[20]
  • Osise midia ti o mo ara mu ju lo ni odun 2015 ni Abryanz Style and Fashion Awards
  • Osise redio obinrin ti o dara julo - Uganda Entertainment Awards ni odun 2016

Awon Eyan ere

àtúnṣe
Odun Ifihan TV Ipa Awọn akọsilẹ
2018 Owurọ @ NTV Gbalejo
NTV Lalẹ Oran
Ọdun 2014 Beneath the lies - The Series Kamali Tenywa Iwaju ipo, ti a ṣẹda nipasẹ Nana Kagga Macpherson
Reserved (TV Show) Ara Rẹ Alejo awọn gbajumọ lori jara wẹẹbu rẹ
Tusker Twende Kazi Ara Rẹ - Oludije lati Uganda Gbajumọ
Ọdun 2013 Tusker Project Fame Ara rẹ - Adajọ Adajọ Adajọ ni Auditions (Uganda)
Odun Fiimu / Fiimu Ipa Awọn akọsilẹ
Ọdun 2010 Irreversable regret
2008 Kiwani: The Movie Pam Dun lẹgbẹẹ Juliana Kanyomozi bi aburo ọmọkunrin rẹ

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. Ninsiima, Audrey. "Flavia Tumusiime, Andrew Kabuura wed at All Saints Cathedraw". The Tower Post. https://thetowerpost.com/2019/01/13/flavia-tumusiime-andrew-kabuura-wed-at-all-saints-cathedral/. Retrieved 19 January 2019. 
  2. "Flavia Tumusiime and Andrew Kabuura welcome their first born". New Vision. https://www.newvision.co.ug/new_vision/news/1517861/flavia-tumusiime-andrew-kabuura-welcome-born. Retrieved 14 April 2020. 
  3. "Flavia Tumusiime: A star glowing on account of humility". Retrieved 11 February 2015. 
  4. "Beneath The Lies Series No More, The Episodes Were Stolen". Archived from the original on 19 February 2015. Retrieved 19 February 2015. 
  5. "30 STORIES FROM FLAVIA’S LIFE AND CAREER". Archived from the original on 2016-03-22.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "Tag Archives: Capital Fm Presenter Flavia". Archived from the original on 24 November 2021. Retrieved 19 February 2015. 
  7. "VJ Blog: Flavia shines on StarGame". Archived from the original on 4 July 2012. Retrieved 19 February 2015. 
  8. "Flavia gets improved Guinness deal". Retrieved 19 February 2015. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  9. "Flavia Tumusiime". Archived from the original on 10 February 2015. Retrieved 19 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  10. "Flavia Tumusiime meets her fan". Archived from the original on 21 June 2017. Retrieved 19 February 2015. 
  11. "Flavia Tumusiime meets her fan". Archived from the original on 21 June 2017. Retrieved 19 February 2015. 
  12. "ALL ABOUT UGANDAN FLAVIA TUMUSIIME". Retrieved 19 February 2015. 
  13. "Flavia Tumusiime: A star glowing on account of humility". Retrieved 11 February 2015. 
  14. "Channel O VJ: Flavia". Archived from the original on 29 October 2011. Retrieved 19 February 2015. 
  15. "VJ Blog: Flavia hosts FESPAD opening!". Archived from the original on 19 January 2012. Retrieved 19 February 2015. 
  16. "Flavia Tumusiime to co-host Big Brother Africa StarGame opening". Archived from the original on 4 March 2016. Retrieved 19 February 2015. 
  17. "Flavia Tumusiime: A star glowing on account of humility". Retrieved 11 February 2015. 
  18. "Flavia Tumusiime meets her fan". Archived from the original on 21 June 2017. Retrieved 19 February 2015. 
  19. https://web.archive.org/web/20150219122828/http://www.theinsider.ug/full-list-of-winners-radio-tv-academy-awards/
  20. https://web.archive.org/web/20150219114849/http://www.newvision.co.ug/mobile/Detail.aspx?NewsID=642644&CatID=397