Flora Suya jẹ́ òṣèré lórílẹ̀-èdè Malawi. Wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré tó dára jù lọ níbi ayẹyẹ kẹfà àti kẹsàn-án tí African Movie Academy Awards.

Flora Suya
Orílẹ̀-èdèMalawi
Iṣẹ́Actress
Gbajúmọ̀ fúnSeasons of a Life (2010)
The Last Fishing Boat (2013)

Iṣẹ́

àtúnṣe

Suya kópa nínú eré Seasons of a Life ní ọdún 2010 pẹ̀lú Tapiwa Gwaza gẹ́gẹ́ bí ọmọ ọ̀dọ̀ tí ọ̀gá rẹ̀ má ń fi ipá ba lòpọ̀.[1] Ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ African Movie Academy Awards fún ipa tí ó kó nínú eré náà.[2] Ní ọdún 2013, ó kópa nínú eré Last Fishing Boat, ipa rẹ̀ nínú eré yìí ló jẹ́ kí wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ AMAA.[3][4] Ní ọdún 2014, ó kópa nínú eré Chenda tí ó ṣọ̀rọ̀ nípa ìpọ́njú tí àwọn àgàn má ń rí.[5][6] Ní ọdún 2016, ó gbé eré My Mothers Story jáde, ó sì kó ipa Tadala nínú eré náà.[7][8]

Àwọn Ìtọ́kàsi

àtúnṣe
  1. admin. "ArtMattan Productions Adds Award-Winning Malawian Film ‘Seasons of a Life’ To Library". Indiewire. Retrieved November 1, 2017. 
  2. admin (March 26, 2010). "AMAA 2010: Malawi’s Flora Suya in top race for Best Actress award". Nigeria Voice. Retrieved November 1, 2017. 
  3. admin (December 2, 2012). "Malawian new film ‘The Last Fishing Boat’ hits the market this month". nyasatimes.com. Retrieved November 1, 2017. 
  4. admin (April 20, 2013). "AMAA 2013: RITA DOMINIC, YVONNE OKORO, FLORA SUYA… WHO BECOMES AFRICA’S QUEEN OF THE SCREEN?". YNaija. Retrieved November 1, 2017. 
  5. Ngiwira, Robert (July 21, 2014). "MALAWIAN ACTRESS, FLORA SUYA TO FEATURE IN ZAMBIAN MOVIE". Face of Malawi. Retrieved November 1, 2017. 
  6. reporter (December 11, 2014). "Flora Suya's Zambian movie launched". MW Nation. Archived from the original on July 10, 2019. Retrieved November 1, 2017. 
  7. Maulidi, Frank (October 13, 2016). "Flora Suya off to USA to premiere her film". Malawi 24. Retrieved November 1, 2017. 
  8. Bisani, Luke (May 31, 2016). "Flora Suya plays single mother in new movie". Malawi 24. Retrieved November 1, 2017.