Màláwì (play /məˈlɑːwi/; Chichewa Àdàkọ:IPA-ny), lonibise bi Orile-ede Olominira ile, je orílẹ̀-èdè àdèmọ́àrinlẹ̀ kan ni guusuilaorun Afrika to je mi mo tele bi Ilẹ̀ Nyasa. O ni bode mo Zambia ni ariwaiwoorun, Tanzania ni ariwailaorun, ati Mozambique ni ilaorun, guusu ati iwoorun. Orile-ede na je pinpinniya si Tanzania ati Mozambique pelu Omi-adagun Malawi. Malawi tobi to 118,000 km2 (45,560 sq mi) pelu awon alabugbe ti idiye won ju 13,900,000 lo. Oluilu re ni Lilongwe, to tun je ilu totobijulo ni be; ikeji totobijulo ni Blantyre ati iketa ni Mzuzu. Malawi bi oruko re wa lati Maravi, oruko atijo fun awon Nyanja ti won budo si be. Won tun unpe orile-ede yi bi "Ọkàn Alọ́wọ́rọ́ Afrika".[8]

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Màláwì
Republic of Malawi
[Chalo cha Malawi, Dziko la Malaŵi] error: {{lang}}: text has italic markup (help)
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
MottoUnity and Freedom
Òkan àti Òmìnira[1]
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè[Mulungu dalitsa Malaŵi] error: {{lang}}: text has italic markup (help)  (Chichewa)
"Oh God Bless Our Land of Malawi"
[2]
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Lilongwe
13°57′S 33°42′E / 13.95°S 33.7°E / -13.95; 33.7
Èdè àlòṣiṣẹ́ English
Chichewa[3]
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2008) Chewa 32.6%
Lomwe 17.6%
Yao 13.5%
Ngoni 11.5%
Tumbuka 8.8%
Nyanja 5.8%
Sena 3.6%
Tonga 2.1%
Ngonde 1%
other 3.5%
Orúkọ aráàlú Ará Màláwì
Ìjọba Orílẹ̀-èdè olómìnira oníàrẹ onísọ̀kan
 -  Ààrẹ Peter Mutharika
 -  Igbákejì Ààrẹ Saulos Chilima
Aṣòfin Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣofin
Ìlómìnira
 -  látọwọ́ Brítánì July 6, 1964 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 118,484 km2 (99th)
45,747 sq mi 
 -  Omi (%) 20.6%
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2010 14,901,000 [4] (64th)
 -  1998 census 9,933,868[5] 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 128.8/km2 (86th)
333.6/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2011
 -  Iye lápapọ̀ $13.901 billion[6] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $860[6] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2011
 -  Àpapọ̀ iye $5.673 billion[6] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $351[6] 
Gini (2008) 38 
HDI (2008) 0.493[7] (low) (160th)
Owóníná Kwacha (D) (MWK (£1.00= 265 kwachas))
Àkókò ilẹ̀àmùrè CAT (UTC+2)
 -  Summer (DST) not observed (UTC+2)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ òsì
Àmìọ̀rọ̀ Internet .mw[3]
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +265[3]
1 Population estimates for this country explicitly take into account the effects of excess mortality due to AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex than would otherwise be expected.
2Information is drawn from the CIA Factbook unless otherwise noted.
ItokasiÀtúnṣe

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Flag
  2. "Malawi National Anthem Lyrics". National Anthem Lyrics. Lyrics on Demand. Retrieved 2008-08-24. 
  3. 3.0 3.1 3.2 "Country profile: Malawi". BBC News Online. BBC. March 13, 2008. Retrieved 2008-08-17. 
  4. http://esa.un.org/UNPP UN estimate for year 2010
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Benson1
  6. 6.0 6.1 6.2 6.3 "Malawi". International Monetary Fund. Retrieved 2012-04-19. 
  7. "2008 Statistical Update: Malawi". United Nations Development Programme. Retrieved 2009-04-19. 
  8. "Malawi, The Warm Heart of Africa". Network of Organizations for Vulnerable & Orphan Children. Retrieved 2011-01-26.