Flying Doctors Nigeria
Flying Doctors of Nigeria jẹ ilé iṣẹ ti o un seto fifi ambulansi gbe ènìyàn. Dr Ola Orekunrin ni óda kalè. [1]
Apejuwe
àtúnṣeO ni olú ọfiisi ni Ilu Eko ati omiran ni Port Harcourt pẹlu ọkọ ofurufu 20 ati oṣiṣẹ 47, 44 ninu wọn jẹ dokita. [2] won Ma un gbe awọn alaisan ti o farapa ati awọn alaisan miran lọ si ile-iwosan, ajo naa ti sísé pèlú aladani àti ìjoba
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ Sabine Cessou (October 30, 2015). "The ten African innovators" (in fr). RFI. http://www.rfi.fr/hebdo/20151030-dix-innovateurs-africains-technologies-science-informatique.
- ↑ "Nigeria’s air ambulance firm is a leap forward for healthcare". Guardian. 12 September 2014. https://www.theguardian.com/global-development/2014/sep/12/nigeria-air-ambulance-firm-healthcare.