Folashade Adekeko Adesiyan Olubanjo
Chief Magistrate Folashade Adekoke Adesiyan Olubanjo (ọjọ́ ìbí Jé ojọ́ Kejì osù keje, ọdún 1968) jẹ́ Adájọ Àgbà tí wọn bí sí Ìpínlè Katsina ní orílé èdè Nàìjíríà, tí ó sì ṣe ìsìn fún ìjọba láti ọọ́ kíni oṣù kẹjọ odun 2003 tí di ọdún 2009. [1]
Folashade Adekoke Adesiyan Olubanjo | |
---|---|
Chief Magistrate of Katsina State | |
In office 2003–2009 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kẹ̀wá 1968 Katsina State, Nigeria |
Alma mater | University of Ibadan |
Occupation | {{Chief Magistrate}| |
marital Status = Àdàkọ:Widow |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀ Ìgbé Ayé
àtúnṣeFolashade tí wón bí sí ìlú Katsina jẹ́ ọmo ìpínlè Oyo, ti ó lọ sí ilé ìwé Alákọ́bẹ̀rẹ̀ tí Fásitì Ibadan tí wọn pè ní University of Ibadan Senior Staff School ní ọdún 1972 sí 1978. Tí ó sì lọ sí ilé ìwé Sẹ́kọ́ńdírì Queen's School ní Àpáta ní ìlú ìbàdàn ní ọdún 1978 sí ọdún 1983, lẹyìn tí ó kúrò ní 1983 ní Queen's School ní ó ṣe bẹ́ẹ̀ ó lọ sí International School tí Fásitì ìlú Ìbàdàn ní ọdún 1983 sí ọdún 1985. Folashade kàwé gboyẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga lórí iṣẹ Òfin ní Fásitì ìlú ìbàdàn ní 1985 sí 1988, bi kò sàì máa lọ sí Nigerian law School tí ó wà ní Victoria island ní ìlú Èkó láti 1988 sí 1989.[2]
Iṣé
àtúnṣeFolashade jẹ́ Agbẹjọro ati Barrister nínú Ofin tí ó sì gboyè 2nd class Upper pẹlu oyè Ọlá (division Honours) ni ọdún 1989, èyí tí ó sì bẹrẹ sí ní ṣíṣe ní odún 1990. Ní ọdún 1990, oṣù Kejì ọdún náà sì oṣù kẹjọ náà ni ọ fí jẹ́ Ìrànlọ́wọ́ sí Òṣìṣẹ́ Amòfin kàn ní ilé ifówopámọ́sí Afribank ni orílé èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ Oluṣakoso Òṣìṣẹ́ nípa òfin fún ilé iṣé EPIWIT Consulting Limited ní ìlú ìbàdàn láti oṣù kẹfà ọdún 1991 sí oṣù tí ó gbèyìn ọdún náà.[2]. Ní oṣù kọkànlá ọdún 1993, o jẹ́ alábojútó ilé iṣé Durtie Holdings Limited ní ìlú ìbàdàn tí tí dì oṣù kẹsán ọdún 1996, lẹyìn èyí ni oníṣe Òfin (legal officer) láti ọdún 1997 sí oṣù kàrún-un ọdún 2003. Folashade ń ṣiṣẹ gẹgẹbi Alakoso Agba (Àbojúto) fún Ilé igbìmọ̀ Ìdájọ ti Ìpínlè Óyo láti ọdún 2003, ọjọ́ kinní oṣù kẹjọ tí tí ó fí dì Adájọ Àgbà (Chief Magistrate Grade II).[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Folashade Adekoke Adesiyan Olubanjo". Wikidata. 1968-07-02. Retrieved 2023-03-15.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 "::::: Hon.Justice F.A.Olubanjo, Federal High Court Nigeria :::::". ::::: Welcome to the Official Website of Federal High Court Nigeria :::::. 2003-07-01. Archived from the original on 2021-11-27. Retrieved 2023-03-15.