Forest Whitaker

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Forest Steven Whitaker (ojoibi July 15, 1961) je osere, atokun, ati oludari filmu ara Amerika to gba Ebun Akademi (Oskar) fun Okunrin Osere Didarajulo Kinni.

Forest Whitaker
Forest Whitaker, March 2007
Ìbí15 Oṣù Keje 1961 (1961-07-15) (ọmọ ọdún 63)
Longview, Texas, U.S.
Iṣẹ́Actor, producer, director
(Àwọn) ìyàwóKeisha Nash (1996–present)