Francistown ní ìlú tí ó tóbi ṣe kejì ní orílẹ̀ èdè Botswana, pẹ̀lú àwọn olùgbé 103,417.[4] Ó wà ní apá ìlà-oòrùn Botswana, ó sì fi kìlómítà irínwó jìnà sí Gaborone. Francistown wà ní ibi tí odò Tati àti Ntshe ti pàdé, àti ní ẹgbẹ́ Odò Shashe (odò tí ó sàn sínú Limpopo) ó sì fi kìlómítà àádọ́rùn-ún jìnà sí àlà Zimbabwe.

Francistown
Àdàkọ:Photomontage
Francistown is located in Botswana
Francistown
Francistown
Map of Botswana showing Francistown
Coordinates: 21°10′25″S 27°30′45″E / 21.17361°S 27.51250°E / -21.17361; 27.51250
Country Botswana
DistrictNorth-East District
Founded1897
Incorporated as a city1997
Named forDaniel Francis
Government
 • TypeCity commission government
 • BodyCity of Francistown Council
 • MayorGodisang Radisigo (BDP)
Area
 • Ìlú79 km2 (31 sq mi)
Elevation
1,001 m (3,284 ft)
Population
 (2022 census)[1]
 • Ìlú103,417
 • Density1,300/km2 (3,400/sq mi)
 • Metro
147,122
Time zoneUTC+2 (Central Africa Time)
 • Summer (DST)UTC+2 (not observed)
Geographical area code[2][3]2XX
ISO 3166 codeBW-FR
ClimateBSh

Èdè tí wọ́n sọ jù ní Francistown ni èdè Kalanga. Àwọn èdè mìíràn ni isiNdebele, ChiShona àti SeTswana.

Ọ̀rọ̀ ajé Francistown

àtúnṣe

Francistown jẹ́ ojú ọ̀nà fún àwọn tí ó ń ṣiṣẹ́ kùsà àti àgbè ní orílẹ̀-èdè Botswana. Ara àwọn ilé isé kùsà tí ó wà níbẹ̀ ni Tati Nickel, tí ó wà lábẹ́ ìdarí Norilsk Nickel, tí ó ṣiṣẹ́ ní Ilẹ̀ kùsà Selkirk àti Phoenix, wọ́n ń ṣe cobalt, copper àti nickel.[5]

Àwọn Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Statistics Bostwana - Census 2022 - Population of cities, towns and villages" (PDF). 
  2. timeanddate.com
  3. Botswana Telecommunications Authority (2009-09-11) (DOC). Botswana (country code +267). International Telecommunication Union. http://www.itu.int/dms_pub/itu-t/oth/02/02/T020200001C0001MSWE.doc. Retrieved 2009-12-27. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. Central Statistics Office (January 2009). "BOTSWANA DEMOGRAPHIC SURVEY 2006" (PDF). Gaborone, Botswana. Archived from the original (PDF) on 2016-09-23. Retrieved 2010-07-25. 
  5. "Norilsk Nickel". Archived from the original on 2010-07-08. Retrieved 2010-07-25.