Fred Amata jẹ́ òṣèré, olùgbéré-jáde àti adarí eré ọmọ.orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó kẹ́kòọ́ gboyè ìmọ̀ nínú ìmọ̀ eré oníṣẹ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Jos, ó di ìlú-mòọ́ká ní ọdún 1986 nínú eré Legacy. Òun ni Ààrẹ fún Directors Guild of Nigeria, láti inú oṣù kejì ọdún 2016.[2][3]

Fred Amata at 2021 AMA Award

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

àtúnṣe
  • Legacy
  • Mortal Inheritance
  • Light & Darkness
  • My Love
  • Keeping Faith: Is That Love?
  • Black Mamba
  • The Return
  • Hand of God
  • Dangerous Desire
  • The London Boy
  • A Kiss From Rose
  • Wheel of Change
  • Hidden Treasures
  • Emotional Hazard
  • Anini
  • Fated
  • She: You Must Obey
  • She2: You Must Obey
  • She3: You Must Obey
  • Family Affair
  • The Amazing Grace
  • The Empire
  • Letters to a Stranger
  • Dear God
  • Blindfold
  • Freedom in Chain
  • Black Gold
  • Black November
  • Road to Redemption

Àwọn amì-ẹ̀yẹ àti ìfisọrí rẹ̀

àtúnṣe
Year Award ceremony Recipient/Nominated work Prize Result
2006 2nd Africa Movie Academy Awards Himself Best Director Wọ́n pèé
Anini Best Film Wọ́n pèé
2007 3rd Africa Movie Academy Awards Himself Best Actor in a Supporting Role Wọ́n pèé
2010 6th Africa Movie Academy Awards Freedom in Chain Best Nigerian Film Wọ́n pèé

Ẹ tún lè wo

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde

àtúnṣe

Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:Nigeria-film-actor-stub