Frederick Sanger, OM, CH, CBE, FRS (ojoibi 13 Osu Kejo 1918) je omo Ilegeesi onimo kemistrialaaye ati elebun Nobel emeji ninu Kemistri. Ohun ni eni kerin (ati enikan soso to wa laaye) to gba Ebun Nobel meji. O gba Ebun Nobel ninu Kemistri ni 1958 ati 1980.

Frederick Sanger
Ìbí13 Oṣù Kẹjọ 1918 (1918-08-13) (ọmọ ọdún 106)
Gloucestershire, England
Ọmọ orílẹ̀-èdèUnited Kingdom
PápáBiochemist
Ilé-ẹ̀kọ́Laboratory of Molecular Biology
Ibi ẹ̀kọ́St John's College, Cambridge
Ó gbajúmọ̀ fúnamino acid sequence of proteins
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Chemistry (1958)
Nobel Prize in Chemistry (1980)