Friedrich Wilhelm Nietzsche (October 15, 1844 – August 25, 1900) (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈfʁiːdʁɪç ˈvɪlhɛlm ˈniːtsʃə]; in English UK: /ˈniːtʃə/, US: /ˈniːtʃi/[1]) je ara Europe ni orundun 19 to je onimo oye ati onimo filologi ijoun. O ko iwe agbeyewo lori esin, iwuwa, asa igbana, imoye ati sayensi, nipa lilo ede Jemani otooto.

Friedrich Nietzsche
Orúkọ Friedrich Nietzsche
Ìbí October 15, 1844
Röcken bei Lützen, Prussia
Aláìsí August 25, 1900(1900-08-25) (ọmọ ọdún 55)
Weimar, Saxony, German Empire
Ìgbà 19th century philosophy
Agbègbè Western Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ Weimar Classicism; precursor to Continental philosophy, existentialism, Individualism, postmodernism, poststructuralism
Ìjẹlógún gangan aesthetics, ethics, ontology, philosophy of history, psychology, value-theory
Àròwá pàtàkì Apollonian and Dionysian, death of God, eternal recurrence, herd-instinct, master-slave morality, Übermensch, perspectivism, will to power, ressentiment, der letzte Mensch
Ìtọwọ́bọ̀wé


ItokasiÀtúnṣe

  1. Wells, John C. (1990). Longman pronunciation dictionary. Harlow, England: Longman. p. 478. ISBN 0582053838.  entry "Nietzsche"