Martin Heidegger (26 September 1889 – 26 May 1976) (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈmaɐ̯tiːn ˈhaɪ̯dɛɡɐ]) je onimoye to ni ipa pataki ara ile Jemani. Iwe re to ko to se koko ni, Being and Time. Heidegger si n fa ariyanjiyan nitori ipa to ko ninu Nazism ati itileyin to ni fun Adolf Hitler.

Martin Heidegger
Orúkọ Martin Heidegger
Ìbí 26 September 1889
Meßkirch, Germany
Aláìsí 26 Oṣù Kàrún 1976 (ọmọ ọdún 86)
Freiburg im Breisgau, Germany
Ìgbà 20th-century philosophy
Agbègbè Western Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ Phenomenology · Hermeneutics · Existentialism
Ìjẹlógún gangan Ontology · Metaphysics · Art · Greek philosophy · Technology · Language · Poetry  · Thinking
Àròwá pàtàkì Dasein · Gestell · Heideggerian terminology
ItokasiÀtúnṣe