Funke Adesiyan
Funke Adesiyan gbọ́ jẹ́ òṣèrébìnrin, Olóṣèlú àti olùrànlọ́wọ́ Aisha Buhari, ìyàwó ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, lórí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ àṣà àti àwùjọ.[3][4]
Funke Adesiyan | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Shukurat Funke Adesiyan[1] |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Olabisi Onabanjo University[2] New York Film Academy |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2003-2011 |
Gbajúmọ̀ fún | Eti Keta, Obinrin Ale |
Political party | All Progressives Congress (2018 to present) |
Awards | Best of Nollywood award Relevation of the year |
Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeAdesiyan jẹ́ ọmọ bíbí Ìlú Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ó lọ ilé-ìwé Time and Tide International School, Ibadan City academy, Saint Anne's School, àti Oriwu College Ikorodu fún ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti Sẹ́kọ́ndírì rẹ̀. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ nínú ìmò òfin ní Yunifásítì Olabisi Onabanjo.[5] Adesiyan kọ́ nípa ṣíṣe fíìmù ní ilé-ìwé New York Film Academy.[6]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- Eti Keta
- Obinrin Ale
- Ayoku Leyin
- Aparo
- Kakaaki
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ The Eagle Online (June 27, 2020). "Buhari's aide eulogises Ajimobi". The Eagle Online. Retrieved August 5, 2022.
- ↑ Akinwale, Funsho (July 28, 2013). "Lagos agent battles star actress, Funke Adesiyan, over Lekki home". The Eagle Online. Retrieved August 5, 2022.
- ↑ "Funke Adesiyan bags Ooni of Ife's excellence award - Punch Newspapers". Punch Newspapers. January 31, 2020. Retrieved August 2, 2022.
- ↑ Bada, Gbenga (October 17, 2019). "Nollywood actress, Funke Adesiyan becomes Aisha Buhari's aide". Pulse Nigeria. Retrieved August 5, 2022.
- ↑ "Acting doesn't pay my bills – Funke Adesiyan - Punch Newspapers". Punch Newspapers. September 11, 2016. Retrieved August 5, 2022.
- ↑ "Celebrities to boycott Tuface's protest - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. January 29, 2017. Retrieved August 5, 2022.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]