Aisha Buhari (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì ọdún 1971)[3]) jẹ́ Obìnrin Àkọ́kọ́ Lorílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Ìyàwó Ààrẹ Muhammadu Buhari , Ààrẹ ana orílẹ̀ ède Nàìjíríà tí sa a re dopin ni ojo kokan din logbon osu kefa odun 2023. Ààrẹ Buhari gbàpò lọ́wọ́ Ààrẹ, Goodluck Jonathan lọ́dún 2015, bẹ́ẹ̀ náà ó tún borí Igbákejì Ààrẹ nígbà ìṣèjọba Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ , Atiku Abubakar nínú ìdìbò tó wáyé lọ́dún 2019 fún sáà Elékejì. Áìshà jẹ́ aṣerunlóge, aṣaralóge àti oǹkọ̀wé.[5][6][7]

Áìshà Bùhárí
Assumed role
29 May 2015
AsíwájúPatience Jonathan
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Aisha Halilu

17 Oṣù Kejì 1971 (1971-02-17) (ọmọ ọdún 53)[1][2][3] former fist
Adamawa, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAPC
(Àwọn) olólùfẹ́
Muhammadu Buhari (m. 1989)
[1][4]
Àwọn ọmọ
RelativesMuhammadu Ribadu (grandfather)
ResidenceAso Villa
ProfessionBusinesswoman

Ìgbà èwe àti ẹbí rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n Áìshà bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì ọdún 19711[8][9][10]ìpínlẹ̀ Adámáwá, lápá àríwá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[11] Bàbá rẹ̀ àgbà Alhaji Muhammadu Ribadu ní mínísítà ààbò àkókò fún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. [12] Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ẹ̀rọ ní bàbá Áìshà Buhari, Màmá rẹ̀ sìn jẹ́ ẹbí Ankali, gbajúgbajà àgbẹ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ̀. Áìshà Bùhárí kàwé àkóbẹ̀rẹ̀ àti gírámà ní ìpínlẹ̀ Adamawa.[13] Lọ́jọ́ kejì, oṣù Kejìlá ọdún 1989, Áìshà fẹ́ Ààrẹ Muhammadu Buhari lọ́kọ,[1][4][14] ẹni tí ó ti bímọ márùn-ún pẹ̀lú àkọ́fẹ́ ìyàwó rẹ̀, Safinatu Yusuf. Áìshà àti Ààrẹ Muhammadu Buhari bímọ márùn-ún àti ọmọ ọmọ kan ṣoṣo fún ara wọn.[15]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 "Nigeria’s New First Lady, Aisha Buhari: 8 Things To Know About The President-Elect's Wife". International Business Times. 2015-04-22. http://www.ibtimes.com/nigerias-new-first-lady-aisha-buhari-8-things-know-about-president-elects-wife-1892079. 
  2. "Aisha Buhari: a new style of First Lady in Nigeria?". news.yahoo.com. Retrieved 17 October 2019. 
  3. 3.0 3.1 "Biography of Aisha Buhari; First Lady Of The Federal Republic Of Nigeria, Politician, Adamawa State Celebrity.". www.nigerianbiography.com. Retrieved 2017-12-20. 
  4. 4.0 4.1 "naijarchives.com - This website is for sale! - naijarchives Resources and Information.". ww1.naijarchives.com. Archived from the original on 17 October 2019. Retrieved 17 October 2019. 
  5. "Aisha Buhari's Book presentation like no other". PunchNews. 
  6. "Aisha Buhari urges fair representation of women in appointments". Vanguard News. 
  7. "Aisha Buhari Meets With APC Women, Youths - Channels Television". Channels Television. 
  8. "Who is Aisha Buhari? | Buhari/Osinbajo Updates". buhariosinbajo.org. Archived from the original on 2017-08-07. Retrieved 2017-12-20. 
  9. "Who Is Aisha Buhari ? | Biography/Profile/Curriculum Vitae Of MRS AISHA BUHARI – Daily Media Nigeria". dailymedia.com.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2017-10-19. Retrieved 2017-12-20. 
  10. "Aisha: Brain and beauty in the villa - Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 2015-04-01. http://www.vanguardngr.com/2015/04/aisha-brain-and-beauty-in-the-villa/. 
  11. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named guardian
  12. Clement Ejiofor. "5 Facts You Need to Know About Aisha Buhari". NEWS.NAIJ.COM - Nigerian & worldwide news. 
  13. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named ibtimes
  14. ""Biography/Profile/Curriculum Vitae Of MRS AISHA BUHARI"". Archived from the original on 31 May 2015. Retrieved 14 June 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  15. "Patience Jonathan’s mistake, lesson for Aisha Buhari – Women". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 30 May 2015. Retrieved 14 June 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)