Funmi Falana jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ ẹni tí ń ṣiṣẹ́ òfin ni ó jẹ́, àti pé olùgbèjà fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin ni ó jẹ́[1]. Funmi Falana ni aya Femi Falana, tí ń ṣe agbẹjọ́rò àti olùgbèjà fún ẹ̀tọ́ àwon ẹ̀dá ènìyàn ti ilẹ̀ Nàìjíríà; òun náà ni ó bí, ọkùnrin akọrin àti òṣèré ilẹ̀ Nàìjíríà Falz. Ilé-ẹ̀kó girama St. Louis Girls, Akure, ní ìpínlẹ̀ Ondo, ni ó ti kàwé. Ó si gba oyè ẹ̀kọ́ Ilé-ìwé gíga ní Físííkì, ìyẹn ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Binin, ó tún tẹ̀ síwájú láti gba oyè nínú ẹ̀kọ́ òfin (LL.B), ìyẹn ilé-èkó gíga ti ìpínlẹ̀ Èkó.[2]

Funmi Falana
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Benin, University of Lagos.
Iṣẹ́Òsìṣẹ́ òfin.
OrganizationWomen Empowerment and Legal Aid (WELA)
Gbajúmọ̀ fúnOlùgbèjà fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin.
Olólùfẹ́Femi Falana
Àwọn ọmọFalz
WebsiteFalanaFalana

Àwon Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Another 14 Year Old, Lucy Ejeh, Kidnapped Converted to Islam in Zamfara". The Breaking Times. 17 March 2016. Archived from the original on 29 May 2016. https://web.archive.org/web/20160529020756/http://www.thebreakingtimes.com/another-14-year-old-lucy-ejeh-kidnapped-converted-to-islam-in-zamfara/. Retrieved 20 June 2016. 
  2. "Funmi Falana". Wikipedia. 2016-06-20. Retrieved 2022-05-22.