Funmilola Aofiyebi-Raimi

Funlola Aofiyebi-RaimiYo-Funlola Aofiyebi-Raimi.ogg Listen tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Abibat Oluwafunmilola Aofiyebi tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí FAR, jẹ́ òṣèrébìnrin ti orílè-èdè Nàìjíríà. Ó ti ṣàfihàn nínú àwọn fíìmù bí i The Figurine, Tinsel àti MTV Shuga.

Funlola Aofiyebi-Raimi
Aofiyebi-Raimi in 2010
Ọjọ́ìbíAbibat Oluwafunmilola Aofiyebi
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànFAR
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1996 Àdàkọ:En dash present
Gbajúmọ̀ fúnTinsel
Olólùfẹ́Olayinka Raimi

Ìgbésí ayé rẹ̀

àtúnṣe

Funlola jẹ́ ọmọ àbígbẹ̀yìn àwọn òbí ọlọ́mọ méje. Ìyá rè jẹ́ onísòwò, bàbá rẹ̀ sì jẹ́ olùdókòwò. Orúkọ FAR tí wọ́n ń pè é mọ́ ọn lórí nígbà tí ó ṣe ìgbéyàwó. FAR tètè farahàn lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán pẹ̀lú àǹtí rẹ̀ Teni Aofiyebi, tó jẹ́ àgbà òṣèré.[1] Ó fẹ́ olùṣèpolówó ọjà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Olayinka Raimi. Látàrí ikú ẹ̀gbọ́n rè, ó pinnu láti yẹra fún ẹ̀rọ-ayélujára fún ìgbà díẹ̀, ó sì padà.[2]

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

àtúnṣe
Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀rí Èsì Ìtọ́ka
2010 Africa Movie Academy Awards (AMAA) Best Actress in a Supporting Role (Figurine) Wọ́n pèé
Nigeria Entertainment Awards Best Actress in a TV Show (Tinsel) Wọ́n pèé
2017 Best of Nollywood Awards Best Supporting Actress –English Wọ́n pèé [4]
2018 Best of Nollywood Awards Best Actress in a Lead Role - English Wọ́n pèé [5]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Suleiman, Yemisi (30 August 2009). "I've always wanted to educate and entertain people - Funlola Aofiyebi-Raimi". Vanguard. Retrieved 29 September 2013. 
  2. "Actress Funlola aofiyebi-Raimi returns to social media after 3-month break to mourn late brother". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2 August 2021. Retrieved 22 July 2022. 
  3. O'Kelly, Aoife (9 October 2019). "Walking with Shadows". Oya Media. Retrieved 23 May 2021. 
  4. "BON Awards 2017: Kannywood’s Ali Nuhu receives Special Recognition Award". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 23 November 2017. Retrieved 7 October 2021. 
  5. "BON Awards 2018: Mercy Aigbe, Tana Adelana shine at 10th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 December 2018. Retrieved 23 December 2019.